KI ELÉYÌÍ OMAAJE ANFAANI FÚN ẸYIN ỌMỌ INÚ GROUP YI
BÁKAN NÁÀ IBADARA TIE BALE ADD ÀWỌN ẸBÍ ATI ỌRẸ YÍN SINU RẸ KÍ ÀWỌN NÁÀ OLÈ MAA JE ÀǸFÀÀNÍ TOWA NIBE
KÒ YỌ ÈLÉ SÌN KAN KAN SILE GBOGBO ÈNÌYÀN LO LÈ WÁ NÍNÚ GROUP YIO ESEUN..
(1.) ARUNSU; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
2..ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo..
3. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.
4. EJE RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.
5. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sise kan oyin je.6. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.
7. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.
8. FUN ARA DIDAN; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.9. FUN IFA RUN AGBON.;Po etu mo oyin igan ma fi pa.10.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.
11. FUN ARAN; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.
12.KI INU OBIRIN GBONA. Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
13.FUN IBA REFUNREFUN;Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
14. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.15. BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.
16. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui mi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).
17. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
18. BI ARA BAUN GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.
19. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo .
20.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.
21.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.
22. OGUN ATOSI. Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.
23.KI ENI TO BA NI ATOGBE ;Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. ma din sugar ku lara.
24.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.
25. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki o fi omi se Haha agbado ki o ma fi Oyin Igan mu bi Tea laro ati lale.
26. KI AGBALAGBA Ma lo Oyin Igan lati mu Tea tabi Ogi O ma un je ki Opolo ji pepe.
Kosiye Meji One
27.Bi ènìyàn bá lọ alu bosa ààayu sínú oyin gidi pelu iye rẹ àti kannafuru láti máa mú ó dára fún jẹ̀díjẹ̀dí òsì man fún ọkùnrin lókun àti agbára láti lè ṣe déédéé lọdọ iyawo rẹ
28.Bi ènìyàn bá lọ èwe sinkinminni pẹlẹbẹ sínú oyin gidi láti máa fi mú ẹ̀kọ́ gbígbóná ó dára fún iko caught èyí keyi
29.Bi abàmì ọ̀gẹ̀dẹ̀ omini tí aba joo pelu obu otoyo ao dáa sínú oyin ao máa laa ó dára fún ogbe inú
30.Eni parapara ao jo papọ ao dá sínú epo Pupa ao máa laa ó dára fún ogbe inú
Gbogbo Ẹyin ti ẹ ba lo ìṣe yí yio bàa yín lára mú amin
No comments:
Post a Comment