Friday, October 26, 2018
🌟🌟🌟🌟IJAPA⭐⭐⭐⭐ IJAPA je ẹranko to gbajúmò kaa kiri agbaye, bákan náà je ẹranko tí èmi rẹ man gùn daada lókè eepe Sungbon kókó nkan ti mofe menu bá lára Ìjàpá ni àwọn ọ̀nà tí àwọn ènìyàn ngba fi dá ara wọn loro tàbí fida eda Egbewon loro, Ǹje ẹ mọ wípé àwọn ìka ènìyàn man fi IJAPA bo ògo ènìyàn mole bakan naa wọn a tún máa fi Ìjàpá wá ògo tipatipa, àìmọye ika Landloard lórí fi irú aburu bayi ja opolopo awon aya lè gbé rẹ lógún, Biwon bati kò ilé wọn yio tí parí ìṣe aburu yí sì inú ilé gbogbo eniti oba gbé inú ilé bayi yio ṣíṣe sise láìní rí kókó kan kojo bio bá ti lowo tele kòtò wọnú ilé yí ojiiji ni owo naa yoo run lowore láìnídìí kosi ni le kúrò ninure nítorí laakaye rẹ koni sì Ayaafi ẹniti o ba je Aladura toje wipe oman fi to san toru ṣe adua irú ẹni bayi ota niwon yio maase pelu landlord rẹ koni feran rẹ nítorí adua to fi ń dena mo agbára èmi òkùnkùn to gbé sínú ilé bí bẹẹ bati kò jáde nínú ilé bayi kia logo rẹ tí ota tí bo móle láti ọjọ́ pipe yio jí dìde, kiise inú ilé nìkan ni àwọn ọkà ènìyàn man se ise burúkú yisi Office, Shops, àti beebee lọ, bákan náà àwọn ọdọ ton fi ipa wá owó ojiiji na manlo Ìjàpá fún fífi wá owó tipátipá, bí anfaani rere sewa lára Ìjàpá bẹẹ naa ni àwọn ojogbon ènìyàn manloo fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ igbiyanju lórí ayé ọmọ ènìyàn lọ́nà todara wọn má ń fi ṣe àṣeje tó dára bakan naa ìgbà Aya Ìjàpá owulo pupo bí ènìyàn bá joo lásán tàbí ènìyàn bá lọ daada pelu Canphor Bíi mẹsan tàbí mewa ao fi ori koo eniti oba man pariwo aya dídùn tioba fi pa aya rẹ yóò sì fi sile lọ́wọ́ kan beena ni igba ẹyin Ìjàpá otun wúlò fún itoju ẹyin didun ao gun kunna daada bíi ti ala koko ao máa fipá ẹyin yio si fiwa Sile, ǸJE Ó MỌ WÍPÉ àwọn ìṣe ìyanu kan wà lára Ìjàpá Bí ènìyàn bá fi igbe Ìjàpá pa ibiti irun bawa lára ènìyàn irun kotun hu jáde mo nibe láéláé, Bí ènìyàn bamu Ìjàpá tioba fi iya odò boo móle di ọjọ kejì eo ni bá Ìjàpá nibe mo eewọ rẹ ni Orí Ìjàpá náà tún wúlò jí Obìnrin bawa ni osu Kẹ̀sán nínú oyun ao tọju ewe abiwere ao lọ èwe yí daada ao tún lọ òri Ìjàpá pelu rẹ ao fi ṣe ẹja aro gbígbé je fún ala boyun yio bí ọmọ náà were ìwọ Ọlọ́run wa sowa lọ́wọ́ ogun aye kio si ṣàánú rẹ fún wa mafi ògo wase apinle fomo èlò miran amin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Àmín Àse
ReplyDelete