Friday, October 26, 2018

ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN PART THREE Ni part two moje koye wá irú àwọn ènìyàn tí wọn man fi egbe lélẹ̀ Moti je ko yewa ni part one wipe nínú Ayanmo tí eda Eniyan kọọ kan gbé wa sílè ayé òun náà nu irawo ẹ̀dá Nínú ọgbọ́n àti ìlà na ẹṣin ibile bí Obìnrin ban woju Olúwa fún Ọmọ tiko bá tete rí ọmọ bí wọn man ba ti o ba lọ sodo àwọn Babaláwo, Olosun, òní sango àti beebelo won yio bàa tọrọ ọmọ lọ́wọ́ òrìṣà wọn yóò ṣìkà nkan fún irú ẹni bẹẹ lorisirisi wípé ó gbodo maase bakan naa bi irú ọmọ bẹẹ bá dáyé tán wọn yóò máa mú ẹ̀jẹ̀ promise tiwon ṣe fún òrìṣà yí lọdọ ọdún nítorí ọmọ òrìṣà ni bakan naa wọn yio ni koni òrìṣà yí ninu ile ìyáre yóò máa bá moju too títí yóò fi dàgbà sungbon ti ìyá ọmọ yí bati kú kòtò di wípé ọmọ yí dàgbà olewu nítorí ọmọ yí yio maa koju àwọn ìṣòro ọlọ́kàn ó jokan nínú irin ajo ayé rẹ òrìṣà tiwon tọrọ rẹ lowore koni jẹki ọmọ yóò ní ìgbà dùn rárá Bakan naa ti ènìyàn baje elesin Musulumi tàbí Christianity Kò gbọ́dọ̀ tọrọ àrànṣe tàbí ọmọ lọ́wọ́ òrìṣà nítorí kio má bàa fi owó arare fa wàhálà ti kiise titie sinu aye re ṣùngbon nínú ayé lóde òní àwọn nkan wọn yí tí poju nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé agbára òkùnkùn ni àwọn ènìyàn fi ń ṣe faari wọn kò gbé ara le agbára Ọlọ́run mo ao máa síwájú sí nínú part four aye gbogbo wa koni dojú ru ó Àmín Continues

No comments:

Post a Comment