Friday, October 26, 2018
AWON ISESI KỌ̀Ọ̀KAN TOWA FÚN ÒNÍ RAWO AFẸ́FẸ́ NÌYÍ ATI AWON IWA WỌN LỌ́KÀN Ó JO KAN PART ONE 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟💯🌟🌟🌟🌟🌟🌟 (1) Àwọn isesi eniti o ba ni irawo AFẸ́FẸ́ man jọ isesi eniti Obanlo irawo omi laimoye ona ìdí nìyí tofi je wipe bí èlò miran bá béèrè lọ́wọ́ àwọn ojogbon wipe oun fe mo irú irawo abawaye òun tiwon yio so wipe irawo Afefe lonlo sungbon toje wipe irawo omi logbewa sáyé nítorí irawo afefe oríṣi risi lowa eniti Obanlo irú irawo òní méjì bayi lan peni irawo Afẹ́fẹ́ omi odara púpò ayé irọrun ni ẹni tí náà yóò gbe awon eniyan bayi kose fi ara we nítorí lailo oogun kan kan gbogbo nkan yio maa rọrùn fún un láti ṣe láyé èmi wọn Asi máa gun dáàda (2) Àwọn ẹni toba je onirawo Afẹ́fẹ́ omi oman wù wọn láti tètè di ènìyàn 'ńlá laye oore nla man sele sinu ìgbésí ayé wọn bakan naa wọn kí ìfẹ́ kí ènìyàn ó di àwọn lọ́wọ́ biwon bafe se nkan laye lati kékeré àwọn ọmọ bayi man tẹnu mo ọ̀rọ̀ púpò ju biwon bafe ki bàbà àwọn tàbí ìyá àwọn Ora nkan fún wọn gbogbo igba niwon yio ma tẹnu mọ nkan naa (3) Bi wọn ba bí àwọn ọmọ bayi nibiti àwọn ìka ènìyàn bá pò bá yowu kí wọn o pọ to òun ni yio Segun gbogbo wọn sungbon wọn ò ní jeki irú ẹni bẹẹ otete ri aje lo bose fe sungbon tio bati kúrò nínú ilé bẹẹ tá bí nínú ìlú bẹẹ yio tete rise (4) Àwọn ọkùnrin bayi tàbí Obìnrin bayi gbọdọ kunfun adua daada nitori àti rí ọkọ tàbí ìyàwó kiise wàhálà ṣùngbon ìṣòro àti rile ọkọ gbé wọn loje ìṣòro wọn man koju ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣòro nínú irin ajo wọn ọmọ aráyé man nílò anfaani wọn sungbon àwọn kiiri àǹfààní gba latodo ènìyàn Ayaafi odò Ọlọ́run Ọba Continue Oore ayọ̀ ẹni kọ̀ọ̀kan wá yóò máa lekun sii 'lojo gbogbo amin
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Amin
ReplyDeleteAmin ase edumare.
ReplyDeleteNje omo omi Le fe iru irswo you
ReplyDeleteSe iyato wa ninu afefe omi Ari afefe nikan
ReplyDeleteIru iyawo so Ni irawo ategunlefe
ReplyDelete