Wednesday, October 17, 2018
EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 KINI WON PE NI ABILU. Abilu ni ise buruku kan ti aye ma nse si eniyan . to ba je obinrin ni won sa abilu si iru obinrin be koni ri oko fe rara ibaje omoge tabi adelebo bi won she ngbe ni won a ma gbe ju sile tabi ko ma ri okunrin pe rara to ba si je okunrin ni koni ri iyawo fe rara awon moju ni obinrin amawo tabi ki won ma fi she jeunjeun... Hmm abilu koki se amutorun wa rara omo araye ni won fi ma nse ara won oko ma nfi abilu kan iyawo beni iyawo gan ma nse abilu si oko papa julo awon to won ba to korawon si le won ma nlo abilu lati maleje ki iru eni be leri oko tabi iyawo Miran femo .... Beni eni ti koti fe iyawo tabi loko ma nse agbako abilu lati owo awon abilu eni tabi lati fi sesan iwa odale fun ololufe toba dale ife hmmmmmm ju gbogbo elo oloun se maje kako si pakute aye oooo. Amin ooooo ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment