Ninu ayé orisirisi eda ènìyàn lowa sungbon tí won gbé àwo ènìyàn sungbon wọn kiise ènìyàn gidi
Igi inú igbó a máa parada di ènìyàn tí yio si maa gbe inú ìlú bẹẹni ẹranko inú igbó náà Man parada gbé papọ pelu ènìyàn laarin ìlú bákan náà ẹja inú omi a máa gbé papọ pelu ènìyàn nínú ìlú bákan náà àwọn ejò snake man parada di ènìyàn tí wọn yio si maa gbe papọ pelu ènìyàn laarin ìlú bẹẹ naa ni ọ̀rọ̀ inú igi tàbí Akijannu burúkú man gbé papọ pelu ènìyàn laarin ìlú ao sóro lórí bí a ṣe lè máa dá wọn mo ní ọ̀kọ̀ọ̀kan tobaya
Sungbon eyiti mofe menu bá funwa ni ti Ọkùnrin tàbí obìnrin ban là àlá wípé lójú orun wipe oun maan saaba sun papọ pelu ejò leè kookan sungbon tí ejò yí kọ́ni ṣe òun ni jamba kankan títí ilé yio fi mọ ọ̀rọ̀ pò lorie
Àlá kọ́kọ́ alayi saaba man wáyé fún ọmọ elegbe omi ti o je wípé ose àdéhùn latode orun wá wípé òun konifi ololufe òun sílè títí láé ọkọ òde ọrùn rẹ lon yọjú sii to parada di ejò beena lórí fún ọkùnrin náà
Irú ẹni bayi yio ni ìṣòro ọkùnrin gidi tàbí obìnrin gidi, irú ẹni bayi kò gbọ́dọ̀ saaba máa ṣe pé fún ènìyàn bẹẹni yio maari inú wọn manle púpò wọn sì man rẹwà daada
Bákan náà àwọn ìka ènìyàn tún má nfi alayi seka fún ènìyàn láti má tètè rona lo ògo ayé rẹ Oropo lorie die tí mole so nìyí ao máa salaye ìyókù nínú live video program e gbìyànjú kí ẹ máa wòó nítorí kò fi bẹ sì ààyè láti má fọwọ́ ko nkan to bẹẹ
Olorun Oba dakun lawa lọ́wọ́ ejò ayé maje kesu ó lágbára lórí ìṣẹ̀dá èmi àti ìwọ àmín
Eseun seun Adupe
ReplyDelete