Friday, October 26, 2018
ITESIWAJU LÓRÍ ISEDA YẸPẸ AWON ÌṢE SI ẸNITI OBANLO IRAWO YEPE IRAWO YEPE ORÍṢIRÍṢI LOWA IRAWO YEPE OMOWA IRAWO YEPE ASALE DESERT WA BÁKAN NÁÀ IRAWO YEPE ÒKÚTA WA AO MAA MẸ́NU BÁWỌN NI Ọ̀KỌ̀Ọ̀KAN 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟 Bí ènìyàn je eniti onlo iseda YẸPẸ OMI irawo yí dára pupọ iseda òní yepe OMI ATI IRAWO OMI ṢE DEEDE ARÁ WỌN ṣùngbon ìyàtò die die lowa pelu wọn Ẹniti o ba fẹ irú ènìyàn bayi Wonkii ni ènìyàn lára iba gbé pò wọn a máa tú ènìyàn lára kódà wonle fi ojú wọn to rẹ fún ènìyàn nibiti inú won dára de Won man pa àṣírí mo daada àǹfààní sípò lára wọn kosi eniti kole báwọn gbé sungbon wọn kí ìfẹ́ ìnira bíi ìjà tàbí nkan ariwo rárá gbogbo ọmọ bibi man pọ lára wọn eyiti oba ni ida dúró tabi kò tètè rí ọmọ bí tàbí tí kori ibú joko ìṣe ọwọ àwọn èmi òkùnkùn ni tabi ki eni bee omaaje eewọ tiko bá iseda rẹ mú wọn man kò onílé àti àlejò mọ́ra sungbon ika ni ọmọ aráyé man fi dípò rere fún wọn Bí ẹni tobanlo iseda yí bawa pelu ẹni ton ta oja ọjà ẹni náà yóò sì máa tá nítorí iseda owó ni iseda yí latara àwọn iseda yí ni àwọn ọmọ ẹgbẹ́ emere Olokuta tí man jáde awon ọmọ ẹgbẹ́ yí burú pupo agídí wọn a sì máa pọ wọn man gbé san lára ẹni toba dojú ìjà kọ wọn ìṣòro ibujoko tàbí nínú ìyàwó gidi sílè man pọ fún won eniti oba ni owo lọ́wọ́ nínú wọn kii sábà tètè rí ọkọ gidi eyiti koba sì tete lowo Ogbodo jìnnà sí ìwà àgbèrè nítorí gbogbo ọkùnrin toba ni àjọṣe pò pelu rẹ ni ona yio maa mafun aomaa tesiwaju lorie iseda ẹni kọ̀ọ̀kan wá koni gba bode ẹ dakun gbogbo nkan ti mo sọ̀rọ̀ lorie dale lórí eniti oti mọ irawo rẹ tele sungbon tofe mọọ síwájú sii Édakun kí enikeni omaa send date of birth kankan sí mio ẹni toba fe mo irú iseda rẹ kò béèrè níbi to ban losi Eseun
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment