Sunday, October 14, 2018
EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Itesiwaju lórí ọkọ ọrùn tàbí aya orun bakan naa bí ase lè tètè dá Elegbe ọmọ mọ àti àwọn ìṣòro kọ̀ọ̀kan towa lábé irawo kọ̀ọ̀kan tí ó ti fà ìṣòro sínú ayé àwọn ènìyàn lao mẹ́nu bá yí ni sise ń tẹ́le, Àlá koko ninu awon opolopo ọ̀rọti moti kọ́kọ́ só seyin nípa ọkọ ọrùn wípé ẹniti o ba ni ọkọ ọrùn tàbí aya orun iru eni bayi òní irawo omi lo gbodo je sungbon ẹniti kò baje onirawo omi towa ni ọkọ ọrùn ìṣe ọwọ àwọn eleye lèyí wọn ofe kí orile ọkọ joko sì tàbí kio lomo laye ni sungbon tio baje wipe ẹniti òní irawo omi ni ìṣòro ọkọ ọrùn tàbí aya orun eleyi kii se yeye rárá confirm nio àìmọye nkan ni ẹniti òní ọkọ ọrùn Man fi ṣe ìbúra latode orun wá èlò miran Man fi ọjọ́ ikùn lè búra, tàbí ojo ìgbéyàwó bakan naa ojo ikomo jáde àti beebee lọ nje ó mọ wípé kodara ki ẹniti òní ọkọ ọrùn ó sáábà máa gba orita mẹta kọjá ní gbogbo ìgbà nítorí ó Man dúró de Ololufe rẹ toba je ìyàwó rè titaye nibe bakan naa ọkọ ọrùn kiije ki oogun oje fún obìnrin tàbí ọkùnrin tí ó bani aya orun ao máa tesiwaju sii lorie eleyi jẹ( Part one) GBOGBO wa ao ni fesu soko laye wa Amin. Edakun ema beere ibeere ninu comment, Mi o ni da eyan lohun mo nibe, Eniba fe beere Irawo re ki o pe ago mi lati dalohun ibeere re. ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Kini irowo October 24
ReplyDelete