Monday, October 15, 2018

Irawo Ina,seri awon irawo ti anso yi je awon irawo to ni agbara pupo, tori ina ti won je, wonje kosemani, olorirere ati oninurere niwon, won je eni ti ola owo pupopupoju, won oni ahun rara, ina kuna won si ma npoju, awon kan ninu won ti e wa tojepe won nife si eso ara ati ti ile pupo, gold ni won ma n fi owo won ra, tori kosi ibi ti awon irawo yi ade ti eoni mon wipe eni nla kan de, iso wo soro won ati ise si won ma n fi won han lopolopo bi eniyan nla, oninu fufu niwon won de ma n ni agidi pupo, awon kan tie wa ninu won tojepe ti won ba nife si oun kan, ti gbogbo eniyan aye yi bawa nso funwon wipe nkan yi kodara, won oni gbo rara, ayafi igba ti won ba to kan abuku bo nidi nkan yen ki oju won toja,won ki gboran boroboro tinu mi ni mase sipoju fun won,won sima ntete dara de eniyan, idi niyi tofi jepe opolopo igba ni awon eniyan ma n dawon, won o ni ori ore rara kosisi ibi ti won ade ti won oki lara won,tori awon kan ninu won, gbogbo ibi ti won ba de ori ni won ma n saba fe je, eyi gan losi ma n fa ogun ati ota pupo fun won, Tori won ma n saba ni ebun pupo pupopupoju, awon kan ninu won bi oba ni won ma n fe se ni gbogbo igba, ojogbon sipoju ninu won, tori ogbon ori won ti poju, awon kan ninu won sima npa sege ninu iro, bi ijapa ologbon ewe ni won se ma nse, won si ma n wadi oun toba se kolofin pupopupo,won si ma n ni ase lenu bi oro lna se ma nmu igi idana beni ase enu won ma nmu Ile, agaga ti won ba fi ibinu soro, oma nsele warawara ni,awon kan ninu won kibimon pupo,won kisi ni iyawo pupo, ojukan ni ada won ma n ni, sugbon awon kan ninu won ma n ni ojukokoro ati afarawe, idi niyi ti won fi ma n se agbere tabi ni iyawo pupo,tabi ki won muti amupara, afarawe lasanlasan ni eleyi, tori koba irawo won mu, sugbon awon kan ninu won le mu igbo tabi siga ju eni keni lo ninu aye yi, tori ina ti irawo won jeyi loma nfun won ni anfani lati le mamu be ,ayafi eyi ti oba mon olorun ni kan ni koki n gbena gori ota ninu won, won si ma n feran ounje jije gan, ati okunrin ati obinrin won kosi eyi ti ki saba mon ina da, won si ma n mon obe se pupo ju awon irawo toku lo, won de ma n ni emin ati sin olorun, won si tun ma n ni Ife si ise olorun, lati kekere won ti awon obi won bafi ese won mon ona olorun, tori gbogbo ise buruku aye yi owo awon irawo yi loma nwa, won ma n ni igboya pupo, oun loun ti won ba si mon amon ju ni won ma n mon, to ri iwadi won ma npoju nipa nkan tanba nife si, opolopo ninu won ni owo won tete manji si owo sugbon won oni fi jonkan monle, odigba ti owo bawa safere ni owo won ki won to wa ma ronu oun toye ki won ti fi owo se,idi niyi tofi jepe nigba ti won aba fi pe omo 35/40,years,obinrin toje afefe tigbodo wa ninu Ile eyi toje okunrin won tabi okunrin toje afefe ti gbodo gbe eyi toje obinrin won sile gege bi iyawo, tori asikoyi yi ni oma nfe re irawo won ti irawo won si ma n fe wo okunkun, sugbon ti won ba ti ni afefe bi iyawo tabi ni oko, oun ni yio ran irawo won lowo lasiko yen lati le bawon fe ina irawo won jo pada, sugbon eyi ti koba mon asiri yi yio lero wipe aye ni oun se oun, awon kan ati e tun masope bi awon oba ni owo awon oni fe iyawo tabi ni oko, besini idamu won yio ma posi aya igba ti won ba to ri irawo afefe ti yio ran irawo won lowo ki nkan tobere si pada bo si ipo,awon toje obinrin won, ki won ma ni suuru, tori won oki fe ni suuru, won ma nfe pase fun oko won ni, tori won ma n ni owo ju oko won lo, sugbon opolopo won ni ki mon wipe oko won na lonba won dana irawo won, tori e ni opolopo won se ma nfe control oko won,idiniyi ti won ki fi saba gbe Ile oko, tori kosi okunrin toma gba ki obinrin ma pase le oun lori, ayafi eyi toba jepe won ti fi pata lu lori abi won ti gberu lati eyin nikan loku ,fun idi eyi awon obinrin won gbudo ni suuru ati iteriba ki won bale pe nile oko dada, awon kan ninu awon irawo yi ma gberaga pupo, won si ma nfe lo agbara ati ipo le awon eniyan lori, sugbon ki won sora fun eleyi tori olorun nikan lole gbe eniyan de opolopo layeyi, awon kan ninu won ma n ni fe si ibalopo pupopupoju, awon kan ninu won si ma n feran eran jije, ki won si sora fun iwa emi ni moto bayi ni mo da bayi, ojo ori re won ni Monday, Wednesday, Thursday, Saturday and Sunday, awo aso ti odara ju fun won ni, pupa foo, ati awo olominosan, pupa ofefe, ati funfun,ki won ma wo dudu rara o, tori kobawon lara mu rara ati rara, okereju won gbudo mani ibalopo pelu oko abi iyawo won ni ekan abi emeji ninu ose, tori oro tiwon koja mofe ni isera ose meta tabi osu kan ti won ba sebe gbogbo nkan aduro si ojukan ni, sugbon ti won base nsumon oko tabi iyawo won ni afefe won ama fe irawo won o dada ni gbogbo igba,iseti oma bawon lara mu ju ni obe jije tabi ise jjo bi imule, ori bibo na si dara fun won, ise asela won ni, ise jagunjagun ni gbogbo ona, kobaje tori Ile tabi tori omi tabi tori afefe, tabi ise olopa tabi ss tabi asogba, ki ama sise ni ile Itura tabi ki ada ile Itura sile, ki ama se ounje ta ni gbogbo ona, ki ama ta aso tabi ran aso, ose sise, tabi irin ikole ni tita, buredi tita tabi ki amase, awon na ni carpenter tabi mechanic, ojise olorun tabi alfa tabi babalawo, won sise nile ise Nepa tabi panapana, tabi gbogbo ise inu orun pata isewon ni, asiwaju sini won ninu oselu, pupo ninu won igi iwe niwon, awon ni won ma n saba ni professor,, ati gbogbo ise toba ti jemon ina ni ise asela won, sugbon iyawo tabi oko ti odaraju funwon ni irawo afefe,tori ti won ba fe irawo min, nkan oni saba lo dede fun won.

10 comments: