Friday, October 26, 2018
ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN PART TWO Ọlọ́run Ọba toda àwa ẹ̀dá ènìyàn oti pín kadara kaluku fún un látode orun wá sílè ayé tí kadara kaluku kosi papọ mọ tí ẹlòmíràn Ise sì ìwà eda kọ̀ọ̀kan pelu ìwà eda ni ao fi mọ wípé irú eda bayi ni ènìyàn yí nítorí bakan naa ẹ̀dá kan kólé so nípa kadara ènìyàn nítorí Ọlọ́run Ọba lo 'n ṣàkóso lórí irin ajo ayé gbogbo àwa ẹ̀dá ènìyàn sungbon ọdún àwọn ènìyàn lẹ́bùn diedie láti leè máa mo nípa ìṣe sì eda kọ̀ọ̀kan àti ìwà eda kọ̀ọ̀kan ẸYINI àwọn ojogbon npeni AKOSEJAYE , IRAWO, àti beebelo Lèyí toje pé bí àwọn tí Ọlọ́run fún imo lorie ban sọ nípa irin ajo ayé ènìyàn yóò dá bí ẹni pé ẹni náà nba ènìyàn gbé nu ilé lofi mo gbogbo àṣírí ayé òun Mo man je koye wá wipe oríṣiríṣi irawo Omi lowa ẹyin ti ema 'n fi Calendar Oloyinbo wo irawo kólé sọ̀rọ̀ lórí eleyi rárá àṣírí ìjìnlè kọ̀ọ̀kan wá lára irawo ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan TALO NI ÌKÒKÒ ẸGBẸ́? NJE DANDAN LOJE FÚN ỌMỌ ELEGBE BEENI BEE SÌ KÒ Aimoye ènìyàn loti wá nínú ìṣòro yí nítorí wọn kò mọ ìtumò ìkòkò egbe àti fífi ìkòkò ẹgbẹ́ lélẹ̀ Bí ènìyàn baje eniti onlo iseda omi tio wa je wipe ijo OLOMO YOYO NI Iru eda bayi gbọ́dọ̀ fi egbe lélẹ̀ ṣùngbon Ogbodo je egbe mímọ irú àwọn ènìyàn bayi wọn saaba man gba ipe láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ègbé tiwon lè dasile nìyí CHURCH , ILE ÌWÉ SCHOOL l, HOSPITAL, MARKET, ILÉ KEWU, CLUB, SOCIETY, POLITICAL PARTY E. T. C. AO MÁA TESIWAJU LÓRÍ Ẹ CONTINUES IN PART THREE
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment