Tuesday, October 23, 2018

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Eyin eniyan mi mofe kie a mo Pataki asiri towa ninu ERU EGBE Lara awon opolopo oro ti moti menu ba lori irawo eda ati awon kan tio romo irawo ko okan lori irawo omi ninu re latari omo elegbe timo si so iru awon omo tio man tibe jade eru egbe je oun kan pataki tiwon man di fun eniti oba ni irawo omi sungbon eniti obani irawo omi ni kan koni Oman di eru egbe eniti oba ni irawo ina naa man di eru egbe titi won naa irawo IYOKU saara nititi won kiise gbogbo oro lale maa so lori facebook nitori eniti oroye koto eniti komo nkankan Eru egbe yi je nkan ti oti gba Aimoye oore danu lowo Aimoye okunrin ati opo lopo obinrin tiko laka kun awon egbe amu to run wa yi yio maa da iru obinrin bee tabi okunrin bee lenu won le maje koni ibujoko, tabi kori aya rere tabi oko rere tabi ko maa bi abiku tabi ki oma ni ase yori lori isere tabi kio maa ni amubo lori oun gbogbo tio ba fe se, Moti je ko yewa wipe Emere omo pinsi ona Aimoye Emere omi, wa bee naani emere odaju wa awon Emere omi awon eleyi man ni aanu oko tio ba fe won ti ko re won je nkan re yio maa dun ni yio lowo daada onare yio maala Sungbon ojo ti obati n se abosi pelu won nkan yio maa daru fun iru okunrin bee tabi obinrin bee Won man jowu pupo bosewa ninu obinrin won bee naa lowa ninu okunrin won Bakan naa tio baje wipe eyi tio ti bimo latorunwa ni tio tun wa ni oko miran laye kio file yewa eje ki nda a duro kie file rii ka daada nitori oro po lorie iwo olorun oba gbogbo omo tio ba funwa laye maje ka rogun aya Jule ka lori won kio bawa se won lolu omo Amin má funwa lomo Agbaana Ọlọ́run ọba má funwa lomo gba jẹ́ ń sinmi Àmín ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN

PART TWO

Ọlọ́run Ọba toda àwa ẹ̀dá ènìyàn oti pín kadara kaluku fún un látode orun wá sílè ayé tí kadara kaluku kosi papọ mọ tí ẹlòmíràn
Ise sì ìwà eda kọ̀ọ̀kan pelu ìwà eda ni ao fi mọ wípé irú eda bayi ni ènìyàn yí nítorí bakan naa ẹ̀dá kan kólé so nípa kadara ènìyàn nítorí Ọlọ́run Ọba lo 'n ṣàkóso lórí irin ajo ayé gbogbo àwa ẹ̀dá ènìyàn sungbon ọdún àwọn ènìyàn lẹ́bùn diedie láti leè máa mo nípa ìṣe sì eda kọ̀ọ̀kan àti ìwà eda kọ̀ọ̀kan ẸYINI àwọn ojogbon npeni AKOSEJAYE , IRAWO, àti beebelo
Lèyí toje pé bí àwọn tí Ọlọ́run fún imo lorie ban sọ nípa irin ajo ayé ènìyàn yóò dá bí ẹni pé ẹni náà nba ènìyàn gbé nu ilé lofi mo gbogbo àṣírí ayé òun
Mo man je koye wá wipe oríṣiríṣi irawo Omi lowa ẹyin ti ema 'n fi Calendar Oloyinbo wo irawo kólé sọ̀rọ̀ lórí eleyi rárá àṣírí ìjìnlè kọ̀ọ̀kan wá lára irawo ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan

TALO NI ÌKÒKÒ ẸGBẸ́? NJE DANDAN LOJE FÚN ỌMỌ ELEGBE BEENI BEE SÌ KÒ

Aimoye ènìyàn loti wá nínú ìṣòro yí nítorí wọn kò mọ ìtumò ìkòkò egbe àti fífi ìkòkò ẹgbẹ́ lélẹ̀

Bí ènìyàn baje eniti onlo iseda omi tio wa je wipe ijo OLOMO YOYO NI
Iru eda bayi gbọ́dọ̀ fi egbe lélẹ̀ ṣùngbon Ogbodo je egbe mímọ irú àwọn ènìyàn bayi wọn saaba man gba ipe láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run
Ègbé tiwon lè dasile nìyí CHURCH , ILE ÌWÉ SCHOOL l, HOSPITAL, MARKET, ILÉ KEWU, CLUB, SOCIETY, POLITICAL PARTY
E. T. C.
AO MÁA TESIWAJU LÓRÍ Ẹ CONTINUES IN PART THREE

1 comment: