Tuesday, October 23, 2018
ADUA YI WAFUN ẸNITI ÀWỌN OTA KIIJE KÍ IRE RẸ OTOO LỌ́WỌ́ TABI ENITI ONA BÁ SAABA MAN DIMO PÚPÒ JÙ ELEYI WAFUN IWO TIO BAJE MÙSÙLÙMÍ ATI CHRISTIAN AO tọju Sugar tí yio pọ dáadáa pelu aṣọ funfun opa kan ao tọju iyọ̀ packet kan laarin aṣọ funfun yí ao dá iyọ̀ sì àárín rẹ ao fi la Leyin náà ao dá sugar yí sì àárí Cross yí ao wa tan Abela funfun mefa Yikare ao wa bere eto adua yí Ao máa kókó ká( orin David 51) ,kia to bere bí abatun parí rẹ ao tú tún ká bakan naa Ao ká( orin David 72) Lee mẹta ao tún ká (ISAIAH 60) láti verse one de ìparí rẹ leemeta Leyin náà ao tún ka Orin Dáfídì 51, leè mẹta ao parie síbè Odindi ọjọ́ mefa lao fi see leyin ọjọ́ kẹfà ao máa mú die nínú sugar yí ao máa fi mú oun toba wuwa ao fi ìyókù ṣe saara fun ọmọdé àti àgbàlagbà tàbí kíá fún àwọn òní bá ara ao máa bù iyọ̀ yí sínú omi láti máa fi we àlè fún àwọn ọmọ wa ni nù iyọ̀ yí láti fi we tàbí ọkọ wá Adua yí dá ra pupo àtun man ló sì àìmọye ọna miran náà gbogbo ẹ lao máa menu bá ní ọ̀kọ̀ọ̀kan Adua yí dára bí a bale maase pelu aawe Olorun yio je ko dara fún gbogbo wa ayé òní te ògo ayé wa mole Àmín Àkíyèsí pàtàkì Bí ààyè bá gba wa daada toje wipe special room wá funwa tí Atile ṣe iṣẹ́ yí tàbí inú church àlè see adua yí nibe láìní ká aṣọ yí nílé fún ọjọ́ mefa ṣùngbon tioba je wipe yaara kan náà lan losi ao maaka aṣọ yí nile bí a bati ń parí eto adua yí bakan naa toba je wipe ninu abela tí abala ló lọ́wọ́ ọkàn tete jotan ao tún mú abela miran nio bí a bá tin parí adua yí ao máa paná orí abela yí bí a bawa parí rẹ tan fún òjò mefa ao ká aṣọ yí nílé àlè dáná sún ni ó odara pupo ao tún máa tesiwaju lórí àwọn eto adua lanla lanla to wúlò fún ìgbésí ayé ọmọ eda ènìyàn ni ìlànà ẹṣin kaluku eo bàa pàdé nínú ìwé tí mo fe gbé jáde ní nu oṣù December tó nbowa yí 10,000 nio egbiyanju kie ni nibe nítorí anfaani pò nínú re gbogbo wa Lao rí ògo wá lo ao ni seru ayé Àmín ÈYÍ NI ETO ADUA YI FÚN ẸNI TOBA JE MÙSÙLÙMÍ Ao lọ wo ayat inú Alquran suratul Hajj Ayat 26 to 27 AO máa ka ayat yí 313 ni ojoojumo pelu èmi ìgbà gbó àpẹẹrẹ tí ao maari ni wípé oore òkèèrè ni yóò má wole wá fún ènìyàn Bio ban taja ọjà rẹ yóò máa tá bio bá wà ọkọ waari ọkọ gidi bioba nwa aya rere waari ṣùngbon àsìkò tí ènìyàn banse adua yí biobaje ọkùnrin sora daada nitori awon obinrin yio maa wa ẹ gidi bẹẹ na lórí fún Obìnrin náà ọkùnrin yio fún ẹ ẹ sora daada ema fi ṣe àgbèrè ó bakan naa Aleka Ayat yí sinu omi laaro kùtùkùtù pelu orúko Ọlọ́run Ọba YAH ALAHU YÀH JAMIU 313 I ao ka Ayat yí sínú omi ni igba 313oruko OLORUN NÁÀ 313ao wá fi omi náà wọn ilé ìyá ja wá pẹ̀lú ogo Ọlọ́run a oba aanu Ọlọ́run pàdé bakan naa ao tún máa tesiwaju pelu aimoye ona ti a tún lè lo AYAT yìsi nínú ìwé tí mofe gbé jáde nínú oṣù December tonbowa yí 10,000 ni ìwé náà àṣírí lanla pò nibe gbìyànjú kio nii lọ́wọ́ gbogbo wa Lao ṣe àṣeyọrí laye wa Amin whtssp me for privacy discussion 08102159160
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment