Friday, October 26, 2018

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Gbogbo wa lamo oruko aworan yi wipe igbale tabi owo lonje Aimoye igba ni moti soro lori die lara iwulore yato fun kia fi gbale ona tio gba wulo po gan an Bio baje eniti oma n saaba la Alakala ni ojo ojumo kio gbe owo tabi igbale duro gege bi eleyi ti enwoyi se duro leyin ilekun behind door inu yara tie fee sun mofi olorun oba bura fune wipe alijannu buruku kankan koni wole bee sini alaburu kan kan koni wa fune mo eyini lara ogbon atinu da awon babawa e danwo bee leo ba a asiri aye ni aye oni koju ija dawa amin ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

ITESIWAJU LÓRÍ ISEDA YẸPẸ AWON ÌṢE SI ẸNITI OBANLO IRAWO YEPE IRAWO YEPE ORÍṢIRÍṢI LOWA IRAWO YEPE OMOWA IRAWO YEPE ASALE DESERT WA BÁKAN NÁÀ IRAWO YEPE ÒKÚTA WA AO MAA MẸ́NU BÁWỌN NI Ọ̀KỌ̀Ọ̀KAN 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟 Bí ènìyàn je eniti onlo iseda YẸPẸ OMI irawo yí dára pupọ iseda òní yepe OMI ATI IRAWO OMI ṢE DEEDE ARÁ WỌN ṣùngbon ìyàtò die die lowa pelu wọn Ẹniti o ba fẹ irú ènìyàn bayi Wonkii ni ènìyàn lára iba gbé pò wọn a máa tú ènìyàn lára kódà wonle fi ojú wọn to rẹ fún ènìyàn nibiti inú won dára de Won man pa àṣírí mo daada àǹfààní sípò lára wọn kosi eniti kole báwọn gbé sungbon wọn kí ìfẹ́ ìnira bíi ìjà tàbí nkan ariwo rárá gbogbo ọmọ bibi man pọ lára wọn eyiti oba ni ida dúró tabi kò tètè rí ọmọ bí tàbí tí kori ibú joko ìṣe ọwọ àwọn èmi òkùnkùn ni tabi ki eni bee omaaje eewọ tiko bá iseda rẹ mú wọn man kò onílé àti àlejò mọ́ra sungbon ika ni ọmọ aráyé man fi dípò rere fún wọn Bí ẹni tobanlo iseda yí bawa pelu ẹni ton ta oja ọjà ẹni náà yóò sì máa tá nítorí iseda owó ni iseda yí latara àwọn iseda yí ni àwọn ọmọ ẹgbẹ́ emere Olokuta tí man jáde awon ọmọ ẹgbẹ́ yí burú pupo agídí wọn a sì máa pọ wọn man gbé san lára ẹni toba dojú ìjà kọ wọn ìṣòro ibujoko tàbí nínú ìyàwó gidi sílè man pọ fún won eniti oba ni owo lọ́wọ́ nínú wọn kii sábà tètè rí ọkọ gidi eyiti koba sì tete lowo Ogbodo jìnnà sí ìwà àgbèrè nítorí gbogbo ọkùnrin toba ni àjọṣe pò pelu rẹ ni ona yio maa mafun aomaa tesiwaju lorie iseda ẹni kọ̀ọ̀kan wá koni gba bode ẹ dakun gbogbo nkan ti mo sọ̀rọ̀ lorie dale lórí eniti oti mọ irawo rẹ tele sungbon tofe mọọ síwájú sii Édakun kí enikeni omaa send date of birth kankan sí mio ẹni toba fe mo irú iseda rẹ kò béèrè níbi to ban losi Eseun

Orúkọ èwe yí a máa jẹ ewe péré gun Oje ewe to gbajúmò dáàda àwọn ojogbon ènìyàn manloo fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ igbiyanju pàápàá wọn man fi èwe yi re ègún kúrò lórí ènìyàn, wọn man fi èwe yi yo ọwọ àwọn èmi òkùnkùn lára ènìyàn wọn man fi èwe yi wo àìsàn lorisirisi Sungbon kókó àti pàtàkì tó tún sá pamó sára èwe yí niyi Igi èwe yí jé ibiti àwọn ọmọ emere ọmọ má ń saaba ṣe ìpàdé pupọ igi abàmì ni igiyi ibi tí wón bá gbìn èwe, yisi wọn man fi igiyi sàmì ibiti wọn ba gbìn igi yisi ni ìwúlò tó tún wà lára rẹ fún gbogbo ala biya mo nìyí Bí ọmọ kékeré banke láìnídì pàtàkì kan ao gun èwe yí lodo daada ao fò odidi agbon kan sii ao fi gba omi Ara èwe yí ao wa ta oyin tàbí epo pupa sii ao máa fún Ọmọ náà mú ao sì tún máa fi paa lára tí obaje wípé àwọn ẹmi òkùnkùn londa ọmọ náà láàmú kíá ni wọn yio kúrò lára ọmọ yí Bakan naa bí wàhálà bá pò fún ènìyàn lórí ìdààmú àwọn èmi òkùnkùn ao ja ewe yí ao tún wà egbo rẹ pẹlu isu ògiri ṣáko eepo obo, egbo tude, ao gun papo kí iru ẹni bẹẹ omaa fi wé ọ̀rọ̀ ẹni náà yio lojutu sì rere lagba Ọlọ́run Ọlọ́run Ọba ìwọ lala gbàrà mafi ìjẹ imuwa sowo ọta wá kio lana ire fún ẹni kọ̀ọ̀kan wá amin

PATAKI OSEYI ATI ÌWÚLÒ RẸ NIYI Bí ènìyàn banmu amubo lori ọkọ tàbí aya pupọ ose yí wúlò fún irú ènìyàn bee Bí ènìyàn bá ń fi ara kò òwú Alantaakun pupo ju owulo fún ènìyàn bee Bí ota bá pò fún ènìyàn tí wọn ń korira ènìyàn owulo fún irú ẹni bee Tí ènìyàn bá dawole nkan ti nkan naa kiipe daru mo eniyan lọ́wọ́ owulo fún irú ẹni bẹẹ Bí ènìyàn bawa ni irin ajo ti ofe kí òun ó tètè rise kio má rí alatako òwú lo fún ẹni bẹẹ Obìnrin tí ó wà nílè oloro gùn tí wàhálà pò nibe bóyá enikan lépa èmi rẹ owulo fún irú ẹni bẹẹ Kii jeki ọfà ota ó wole sì ènìyàn lára òsì man dènà asasi Bí ènìyàn báni àwọn ọmọde lọ́wọ́ odara fún wọn nítorí ààbò Ọlọ́run Ọba Eyonu gidi ni a sina gidi ni bakan naa otun ń dènà alakala Otun dara fún Obìnrin tí koni ibu joko Owulo fún oga ilé ìṣe tàbí ọmọ ek ose tàbí ọmọ ilẹ̀ ìwé kosi ọjọ orí tí kólé loo bakan naa ọmọ ìkòkò lè loo Orúkọ Ọlọ́run lafi see Otun wúlò fáwọn nkan pàtàkì kan tí ao lè máa ṣàlàyé rẹ bayi eniti o bára ose yí lao ṣàlàyé gbogbo rẹ fún bakan naa kose pín sí méjì ori kan ose kan nio Kiise ose yí nìkan nio pelu ipara rẹ nio má fojú di I wípé orí net loti bàa pàdé ó àwọn tó dáa mi niwon ni tun fe ki see jáde owore kopo rárá ìwọ tio bati fe nínú èyí ni àwọn tí èlé rí ose yí ra lọdọ wọnv tiwọn yio tún ṣàlàyé rẹ fún yín yekeyeke bie sele loo (1)EO ríi ra ni Bayeku Community bus stop Cross to other side and ask for Alhaji Solaudeen, 08027380717,08177396458, Ikorodu Lagos (2) Enter bus to Ajah alight at Agungi bus stop cross the road to other side then, take bike to Ajiran drop at Ojomu Central Mosque Ask NUMBER 17 Bakare Avenue Ajiran Eti Osa Lagos , 08030473635, 08175929955 (3) AKINOLA STREET NUMBER 29 Bariga second room by the Wright Lagos Sheik Luqmon Olasunkanmi Ayandare +2348089038658, +2348032983298 +2348133155111 +2347059780034 +2348179391932 +2348180023385 +2348089522187 HOME ADRESS AKINOLA STREET NUMBER 29 Bariga second room by the Wright Lagos Nigeria 🇳🇬

AWON ISESI KỌ̀Ọ̀KAN TOWA FÚN ÒNÍ RAWO AFẸ́FẸ́ NÌYÍ ATI AWON IWA WỌN LỌ́KÀN Ó JO KAN PART ONE 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟💯🌟🌟🌟🌟🌟🌟 (1) Àwọn isesi eniti o ba ni irawo AFẸ́FẸ́ man jọ isesi eniti Obanlo irawo omi laimoye ona ìdí nìyí tofi je wipe bí èlò miran bá béèrè lọ́wọ́ àwọn ojogbon wipe oun fe mo irú irawo abawaye òun tiwon yio so wipe irawo Afefe lonlo sungbon toje wipe irawo omi logbewa sáyé nítorí irawo afefe oríṣi risi lowa eniti Obanlo irú irawo òní méjì bayi lan peni irawo Afẹ́fẹ́ omi odara púpò ayé irọrun ni ẹni tí náà yóò gbe awon eniyan bayi kose fi ara we nítorí lailo oogun kan kan gbogbo nkan yio maa rọrùn fún un láti ṣe láyé èmi wọn Asi máa gun dáàda (2) Àwọn ẹni toba je onirawo Afẹ́fẹ́ omi oman wù wọn láti tètè di ènìyàn 'ńlá laye oore nla man sele sinu ìgbésí ayé wọn bakan naa wọn kí ìfẹ́ kí ènìyàn ó di àwọn lọ́wọ́ biwon bafe se nkan laye lati kékeré àwọn ọmọ bayi man tẹnu mo ọ̀rọ̀ púpò ju biwon bafe ki bàbà àwọn tàbí ìyá àwọn Ora nkan fún wọn gbogbo igba niwon yio ma tẹnu mọ nkan naa (3) Bi wọn ba bí àwọn ọmọ bayi nibiti àwọn ìka ènìyàn bá pò bá yowu kí wọn o pọ to òun ni yio Segun gbogbo wọn sungbon wọn ò ní jeki irú ẹni bẹẹ otete ri aje lo bose fe sungbon tio bati kúrò nínú ilé bẹẹ tá bí nínú ìlú bẹẹ yio tete rise (4) Àwọn ọkùnrin bayi tàbí Obìnrin bayi gbọdọ kunfun adua daada nitori àti rí ọkọ tàbí ìyàwó kiise wàhálà ṣùngbon ìṣòro àti rile ọkọ gbé wọn loje ìṣòro wọn man koju ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣòro nínú irin ajo wọn ọmọ aráyé man nílò anfaani wọn sungbon àwọn kiiri àǹfààní gba latodo ènìyàn Ayaafi odò Ọlọ́run Ọba Continue Oore ayọ̀ ẹni kọ̀ọ̀kan wá yóò máa lekun sii 'lojo gbogbo amin

🌟🌟🌟🌟IJAPA⭐⭐⭐⭐ IJAPA je ẹranko to gbajúmò kaa kiri agbaye, bákan náà je ẹranko tí èmi rẹ man gùn daada lókè eepe Sungbon kókó nkan ti mofe menu bá lára Ìjàpá ni àwọn ọ̀nà tí àwọn ènìyàn ngba fi dá ara wọn loro tàbí fida eda Egbewon loro, Ǹje ẹ mọ wípé àwọn ìka ènìyàn man fi IJAPA bo ògo ènìyàn mole bakan naa wọn a tún máa fi Ìjàpá wá ògo tipatipa, àìmọye ika Landloard lórí fi irú aburu bayi ja opolopo awon aya lè gbé rẹ lógún, Biwon bati kò ilé wọn yio tí parí ìṣe aburu yí sì inú ilé gbogbo eniti oba gbé inú ilé bayi yio ṣíṣe sise láìní rí kókó kan kojo bio bá ti lowo tele kòtò wọnú ilé yí ojiiji ni owo naa yoo run lowore láìnídìí kosi ni le kúrò ninure nítorí laakaye rẹ koni sì Ayaafi ẹniti o ba je Aladura toje wipe oman fi to san toru ṣe adua irú ẹni bayi ota niwon yio maase pelu landlord rẹ koni feran rẹ nítorí adua to fi ń dena mo agbára èmi òkùnkùn to gbé sínú ilé bí bẹẹ bati kò jáde nínú ilé bayi kia logo rẹ tí ota tí bo móle láti ọjọ́ pipe yio jí dìde, kiise inú ilé nìkan ni àwọn ọkà ènìyàn man se ise burúkú yisi Office, Shops, àti beebee lọ, bákan náà àwọn ọdọ ton fi ipa wá owó ojiiji na manlo Ìjàpá fún fífi wá owó tipátipá, bí anfaani rere sewa lára Ìjàpá bẹẹ naa ni àwọn ojogbon ènìyàn manloo fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ igbiyanju lórí ayé ọmọ ènìyàn lọ́nà todara wọn má ń fi ṣe àṣeje tó dára bakan naa ìgbà Aya Ìjàpá owulo pupo bí ènìyàn bá joo lásán tàbí ènìyàn bá lọ daada pelu Canphor Bíi mẹsan tàbí mewa ao fi ori koo eniti oba man pariwo aya dídùn tioba fi pa aya rẹ yóò sì fi sile lọ́wọ́ kan beena ni igba ẹyin Ìjàpá otun wúlò fún itoju ẹyin didun ao gun kunna daada bíi ti ala koko ao máa fipá ẹyin yio si fiwa Sile, ǸJE Ó MỌ WÍPÉ àwọn ìṣe ìyanu kan wà lára Ìjàpá Bí ènìyàn bá fi igbe Ìjàpá pa ibiti irun bawa lára ènìyàn irun kotun hu jáde mo nibe láéláé, Bí ènìyàn bamu Ìjàpá tioba fi iya odò boo móle di ọjọ kejì eo ni bá Ìjàpá nibe mo eewọ rẹ ni Orí Ìjàpá náà tún wúlò jí Obìnrin bawa ni osu Kẹ̀sán nínú oyun ao tọju ewe abiwere ao lọ èwe yí daada ao tún lọ òri Ìjàpá pelu rẹ ao fi ṣe ẹja aro gbígbé je fún ala boyun yio bí ọmọ náà were ìwọ Ọlọ́run wa sowa lọ́wọ́ ogun aye kio si ṣàánú rẹ fún wa mafi ògo wase apinle fomo èlò miran amin

ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN PART THREE Ni part two moje koye wá irú àwọn ènìyàn tí wọn man fi egbe lélẹ̀ Moti je ko yewa ni part one wipe nínú Ayanmo tí eda Eniyan kọọ kan gbé wa sílè ayé òun náà nu irawo ẹ̀dá Nínú ọgbọ́n àti ìlà na ẹṣin ibile bí Obìnrin ban woju Olúwa fún Ọmọ tiko bá tete rí ọmọ bí wọn man ba ti o ba lọ sodo àwọn Babaláwo, Olosun, òní sango àti beebelo won yio bàa tọrọ ọmọ lọ́wọ́ òrìṣà wọn yóò ṣìkà nkan fún irú ẹni bẹẹ lorisirisi wípé ó gbodo maase bakan naa bi irú ọmọ bẹẹ bá dáyé tán wọn yóò máa mú ẹ̀jẹ̀ promise tiwon ṣe fún òrìṣà yí lọdọ ọdún nítorí ọmọ òrìṣà ni bakan naa wọn yio ni koni òrìṣà yí ninu ile ìyáre yóò máa bá moju too títí yóò fi dàgbà sungbon ti ìyá ọmọ yí bati kú kòtò di wípé ọmọ yí dàgbà olewu nítorí ọmọ yí yio maa koju àwọn ìṣòro ọlọ́kàn ó jokan nínú irin ajo ayé rẹ òrìṣà tiwon tọrọ rẹ lowore koni jẹki ọmọ yóò ní ìgbà dùn rárá Bakan naa ti ènìyàn baje elesin Musulumi tàbí Christianity Kò gbọ́dọ̀ tọrọ àrànṣe tàbí ọmọ lọ́wọ́ òrìṣà nítorí kio má bàa fi owó arare fa wàhálà ti kiise titie sinu aye re ṣùngbon nínú ayé lóde òní àwọn nkan wọn yí tí poju nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé agbára òkùnkùn ni àwọn ènìyàn fi ń ṣe faari wọn kò gbé ara le agbára Ọlọ́run mo ao máa síwájú sí nínú part four aye gbogbo wa koni dojú ru ó Àmín Continues

ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN PART TWO Ọlọ́run Ọba toda àwa ẹ̀dá ènìyàn oti pín kadara kaluku fún un látode orun wá sílè ayé tí kadara kaluku kosi papọ mọ tí ẹlòmíràn Ise sì ìwà eda kọ̀ọ̀kan pelu ìwà eda ni ao fi mọ wípé irú eda bayi ni ènìyàn yí nítorí bakan naa ẹ̀dá kan kólé so nípa kadara ènìyàn nítorí Ọlọ́run Ọba lo 'n ṣàkóso lórí irin ajo ayé gbogbo àwa ẹ̀dá ènìyàn sungbon ọdún àwọn ènìyàn lẹ́bùn diedie láti leè máa mo nípa ìṣe sì eda kọ̀ọ̀kan àti ìwà eda kọ̀ọ̀kan ẸYINI àwọn ojogbon npeni AKOSEJAYE , IRAWO, àti beebelo Lèyí toje pé bí àwọn tí Ọlọ́run fún imo lorie ban sọ nípa irin ajo ayé ènìyàn yóò dá bí ẹni pé ẹni náà nba ènìyàn gbé nu ilé lofi mo gbogbo àṣírí ayé òun Mo man je koye wá wipe oríṣiríṣi irawo Omi lowa ẹyin ti ema 'n fi Calendar Oloyinbo wo irawo kólé sọ̀rọ̀ lórí eleyi rárá àṣírí ìjìnlè kọ̀ọ̀kan wá lára irawo ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan TALO NI ÌKÒKÒ ẸGBẸ́? NJE DANDAN LOJE FÚN ỌMỌ ELEGBE BEENI BEE SÌ KÒ Aimoye ènìyàn loti wá nínú ìṣòro yí nítorí wọn kò mọ ìtumò ìkòkò egbe àti fífi ìkòkò ẹgbẹ́ lélẹ̀ Bí ènìyàn baje eniti onlo iseda omi tio wa je wipe ijo OLOMO YOYO NI Iru eda bayi gbọ́dọ̀ fi egbe lélẹ̀ ṣùngbon Ogbodo je egbe mímọ irú àwọn ènìyàn bayi wọn saaba man gba ipe láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ègbé tiwon lè dasile nìyí CHURCH , ILE ÌWÉ SCHOOL l, HOSPITAL, MARKET, ILÉ KEWU, CLUB, SOCIETY, POLITICAL PARTY E. T. C. AO MÁA TESIWAJU LÓRÍ Ẹ CONTINUES IN PART THREE

KI ELÉYÌÍ OMAAJE ANFAANI FÚN ẸYIN ỌMỌ INÚ GROUP YI

BÁKAN NÁÀ IBADARA TIE BALE ADD ÀWỌN ẸBÍ ATI ỌRẸ YÍN SINU RẸ KÍ ÀWỌN NÁÀ OLÈ MAA JE ÀǸFÀÀNÍ TOWA NIBE
KÒ YỌ ÈLÉ SÌN KAN KAN SILE GBOGBO ÈNÌYÀN LO LÈ WÁ NÍNÚ GROUP YIO ESEUN..

(1.) ARUNSU; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
2..ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo..
3. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.
4. EJE RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.
5. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sise kan oyin je.6. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.
7. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.
8. FUN ARA DIDAN; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.9. FUN IFA RUN AGBON.;Po etu mo oyin igan ma fi pa.10.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa ara.
11. FUN ARAN; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.
12.KI INU OBIRIN GBONA. Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.
13.FUN IBA REFUNREFUN;Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
14. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.15. BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.
16. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui mi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).
17. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
18. BI ARA BAUN GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.
19. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta lojumo .
20.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta lojumo.
21.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.
22. OGUN ATOSI. Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.
23.KI ENI TO BA NI ATOGBE ;Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. ma din sugar ku lara.
24.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.
25. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki o fi omi se Haha agbado ki o ma fi Oyin Igan mu bi Tea laro ati lale.
26. KI AGBALAGBA Ma lo Oyin Igan lati mu Tea tabi Ogi O ma un je ki Opolo ji pepe.
Kosiye Meji One
27.Bi ènìyàn bá lọ alu bosa ààayu sínú oyin gidi pelu iye rẹ àti kannafuru láti máa mú ó dára fún jẹ̀díjẹ̀dí òsì man fún ọkùnrin lókun àti agbára láti lè ṣe déédéé lọdọ iyawo rẹ
28.Bi ènìyàn bá lọ èwe sinkinminni pẹlẹbẹ sínú oyin gidi láti máa fi mú ẹ̀kọ́ gbígbóná ó dára fún iko caught èyí keyi
29.Bi abàmì ọ̀gẹ̀dẹ̀ omini tí aba joo pelu obu otoyo ao dáa sínú oyin ao máa laa ó dára fún ogbe inú
30.Eni parapara ao jo papọ ao dá sínú epo Pupa ao máa laa ó dára fún ogbe inú
Gbogbo Ẹyin ti ẹ ba lo ìṣe yí yio bàa yín lára mú amin

Tuesday, October 23, 2018

ADUA YI WAFUN ẸNITI ÀWỌN OTA KIIJE KÍ IRE RẸ OTOO LỌ́WỌ́ TABI ENITI ONA BÁ SAABA MAN DIMO PÚPÒ JÙ ELEYI WAFUN IWO TIO BAJE MÙSÙLÙMÍ ATI CHRISTIAN AO tọju Sugar tí yio pọ dáadáa pelu aṣọ funfun opa kan ao tọju iyọ̀ packet kan laarin aṣọ funfun yí ao dá iyọ̀ sì àárín rẹ ao fi la Leyin náà ao dá sugar yí sì àárí Cross yí ao wa tan Abela funfun mefa Yikare ao wa bere eto adua yí Ao máa kókó ká( orin David 51) ,kia to bere bí abatun parí rẹ ao tú tún ká bakan naa Ao ká( orin David 72) Lee mẹta ao tún ká (ISAIAH 60) láti verse one de ìparí rẹ leemeta Leyin náà ao tún ka Orin Dáfídì 51, leè mẹta ao parie síbè Odindi ọjọ́ mefa lao fi see leyin ọjọ́ kẹfà ao máa mú die nínú sugar yí ao máa fi mú oun toba wuwa ao fi ìyókù ṣe saara fun ọmọdé àti àgbàlagbà tàbí kíá fún àwọn òní bá ara ao máa bù iyọ̀ yí sínú omi láti máa fi we àlè fún àwọn ọmọ wa ni nù iyọ̀ yí láti fi we tàbí ọkọ wá Adua yí dá ra pupo àtun man ló sì àìmọye ọna miran náà gbogbo ẹ lao máa menu bá ní ọ̀kọ̀ọ̀kan Adua yí dára bí a bale maase pelu aawe Olorun yio je ko dara fún gbogbo wa ayé òní te ògo ayé wa mole Àmín Àkíyèsí pàtàkì Bí ààyè bá gba wa daada toje wipe special room wá funwa tí Atile ṣe iṣẹ́ yí tàbí inú church àlè see adua yí nibe láìní ká aṣọ yí nílé fún ọjọ́ mefa ṣùngbon tioba je wipe yaara kan náà lan losi ao maaka aṣọ yí nile bí a bati ń parí eto adua yí bakan naa toba je wipe ninu abela tí abala ló lọ́wọ́ ọkàn tete jotan ao tún mú abela miran nio bí a bá tin parí adua yí ao máa paná orí abela yí bí a bawa parí rẹ tan fún òjò mefa ao ká aṣọ yí nílé àlè dáná sún ni ó odara pupo ao tún máa tesiwaju lórí àwọn eto adua lanla lanla to wúlò fún ìgbésí ayé ọmọ eda ènìyàn ni ìlànà ẹṣin kaluku eo bàa pàdé nínú ìwé tí mo fe gbé jáde ní nu oṣù December tó nbowa yí 10,000 nio egbiyanju kie ni nibe nítorí anfaani pò nínú re gbogbo wa Lao rí ògo wá lo ao ni seru ayé Àmín ÈYÍ NI ETO ADUA YI FÚN ẸNI TOBA JE MÙSÙLÙMÍ Ao lọ wo ayat inú Alquran suratul Hajj Ayat 26 to 27 AO máa ka ayat yí 313 ni ojoojumo pelu èmi ìgbà gbó àpẹẹrẹ tí ao maari ni wípé oore òkèèrè ni yóò má wole wá fún ènìyàn Bio ban taja ọjà rẹ yóò máa tá bio bá wà ọkọ waari ọkọ gidi bioba nwa aya rere waari ṣùngbon àsìkò tí ènìyàn banse adua yí biobaje ọkùnrin sora daada nitori awon obinrin yio maa wa ẹ gidi bẹẹ na lórí fún Obìnrin náà ọkùnrin yio fún ẹ ẹ sora daada ema fi ṣe àgbèrè ó bakan naa Aleka Ayat yí sinu omi laaro kùtùkùtù pelu orúko Ọlọ́run Ọba YAH ALAHU YÀH JAMIU 313 I ao ka Ayat yí sínú omi ni igba 313oruko OLORUN NÁÀ 313ao wá fi omi náà wọn ilé ìyá ja wá pẹ̀lú ogo Ọlọ́run a oba aanu Ọlọ́run pàdé bakan naa ao tún máa tesiwaju pelu aimoye ona ti a tún lè lo AYAT yìsi nínú ìwé tí mofe gbé jáde nínú oṣù December tonbowa yí 10,000 ni ìwé náà àṣírí lanla pò nibe gbìyànjú kio nii lọ́wọ́ gbogbo wa Lao ṣe àṣeyọrí laye wa Amin whtssp me for privacy discussion 08102159160

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Eyin eniyan mi mofe kie a mo Pataki asiri towa ninu ERU EGBE Lara awon opolopo oro ti moti menu ba lori irawo eda ati awon kan tio romo irawo ko okan lori irawo omi ninu re latari omo elegbe timo si so iru awon omo tio man tibe jade eru egbe je oun kan pataki tiwon man di fun eniti oba ni irawo omi sungbon eniti obani irawo omi ni kan koni Oman di eru egbe eniti oba ni irawo ina naa man di eru egbe titi won naa irawo IYOKU saara nititi won kiise gbogbo oro lale maa so lori facebook nitori eniti oroye koto eniti komo nkankan Eru egbe yi je nkan ti oti gba Aimoye oore danu lowo Aimoye okunrin ati opo lopo obinrin tiko laka kun awon egbe amu to run wa yi yio maa da iru obinrin bee tabi okunrin bee lenu won le maje koni ibujoko, tabi kori aya rere tabi oko rere tabi ko maa bi abiku tabi ki oma ni ase yori lori isere tabi kio maa ni amubo lori oun gbogbo tio ba fe se, Moti je ko yewa wipe Emere omo pinsi ona Aimoye Emere omi, wa bee naani emere odaju wa awon Emere omi awon eleyi man ni aanu oko tio ba fe won ti ko re won je nkan re yio maa dun ni yio lowo daada onare yio maala Sungbon ojo ti obati n se abosi pelu won nkan yio maa daru fun iru okunrin bee tabi obinrin bee Won man jowu pupo bosewa ninu obinrin won bee naa lowa ninu okunrin won Bakan naa tio baje wipe eyi tio ti bimo latorunwa ni tio tun wa ni oko miran laye kio file yewa eje ki nda a duro kie file rii ka daada nitori oro po lorie iwo olorun oba gbogbo omo tio ba funwa laye maje ka rogun aya Jule ka lori won kio bawa se won lolu omo Amin má funwa lomo Agbaana Ọlọ́run ọba má funwa lomo gba jẹ́ ń sinmi Àmín ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

ÌKÒKÒ ẸGBẸ́ TÀBÍ FÍFI ÈGBÉ LÉLẸ̀ FÚN ÈNÌYÀN

PART TWO

Ọlọ́run Ọba toda àwa ẹ̀dá ènìyàn oti pín kadara kaluku fún un látode orun wá sílè ayé tí kadara kaluku kosi papọ mọ tí ẹlòmíràn
Ise sì ìwà eda kọ̀ọ̀kan pelu ìwà eda ni ao fi mọ wípé irú eda bayi ni ènìyàn yí nítorí bakan naa ẹ̀dá kan kólé so nípa kadara ènìyàn nítorí Ọlọ́run Ọba lo 'n ṣàkóso lórí irin ajo ayé gbogbo àwa ẹ̀dá ènìyàn sungbon ọdún àwọn ènìyàn lẹ́bùn diedie láti leè máa mo nípa ìṣe sì eda kọ̀ọ̀kan àti ìwà eda kọ̀ọ̀kan ẸYINI àwọn ojogbon npeni AKOSEJAYE , IRAWO, àti beebelo
Lèyí toje pé bí àwọn tí Ọlọ́run fún imo lorie ban sọ nípa irin ajo ayé ènìyàn yóò dá bí ẹni pé ẹni náà nba ènìyàn gbé nu ilé lofi mo gbogbo àṣírí ayé òun
Mo man je koye wá wipe oríṣiríṣi irawo Omi lowa ẹyin ti ema 'n fi Calendar Oloyinbo wo irawo kólé sọ̀rọ̀ lórí eleyi rárá àṣírí ìjìnlè kọ̀ọ̀kan wá lára irawo ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan

TALO NI ÌKÒKÒ ẸGBẸ́? NJE DANDAN LOJE FÚN ỌMỌ ELEGBE BEENI BEE SÌ KÒ

Aimoye ènìyàn loti wá nínú ìṣòro yí nítorí wọn kò mọ ìtumò ìkòkò egbe àti fífi ìkòkò ẹgbẹ́ lélẹ̀

Bí ènìyàn baje eniti onlo iseda omi tio wa je wipe ijo OLOMO YOYO NI
Iru eda bayi gbọ́dọ̀ fi egbe lélẹ̀ ṣùngbon Ogbodo je egbe mímọ irú àwọn ènìyàn bayi wọn saaba man gba ipe láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run
Ègbé tiwon lè dasile nìyí CHURCH , ILE ÌWÉ SCHOOL l, HOSPITAL, MARKET, ILÉ KEWU, CLUB, SOCIETY, POLITICAL PARTY
E. T. C.
AO MÁA TESIWAJU LÓRÍ Ẹ CONTINUES IN PART THREE

Wednesday, October 17, 2018

Ninu ayé orisirisi eda ènìyàn lowa sungbon tí won gbé àwo ènìyàn sungbon wọn kiise ènìyàn gidi
Igi inú igbó a máa parada di ènìyàn tí yio si maa gbe inú ìlú bẹẹni ẹranko inú igbó náà Man parada gbé papọ pelu ènìyàn laarin ìlú bákan náà ẹja inú omi a máa gbé papọ pelu ènìyàn nínú ìlú bákan náà àwọn ejò snake man parada di ènìyàn tí wọn yio si maa gbe papọ pelu ènìyàn laarin ìlú bẹẹ naa ni ọ̀rọ̀ inú igi tàbí Akijannu burúkú man gbé papọ pelu ènìyàn laarin ìlú ao sóro lórí bí a ṣe lè máa dá wọn mo ní ọ̀kọ̀ọ̀kan tobaya
Sungbon eyiti mofe menu bá funwa ni ti Ọkùnrin tàbí obìnrin ban là àlá wípé lójú orun wipe oun maan saaba sun papọ pelu ejò leè kookan sungbon tí ejò yí kọ́ni ṣe òun ni jamba kankan títí ilé yio fi mọ ọ̀rọ̀ pò lorie
Àlá kọ́kọ́ alayi saaba man wáyé fún ọmọ elegbe omi ti o je wípé ose àdéhùn latode orun wá wípé òun konifi ololufe òun sílè títí láé ọkọ òde ọrùn rẹ lon yọjú sii to parada di ejò beena lórí fún ọkùnrin náà
Irú ẹni bayi yio ni ìṣòro ọkùnrin gidi tàbí obìnrin gidi, irú ẹni bayi kò gbọ́dọ̀ saaba máa ṣe pé fún ènìyàn bẹẹni yio maari inú wọn manle púpò wọn sì man rẹwà daada
Bákan náà àwọn ìka ènìyàn tún má nfi alayi seka fún ènìyàn láti má tètè rona lo ògo ayé rẹ Oropo lorie die tí mole so nìyí ao máa salaye ìyókù nínú live video program e gbìyànjú kí ẹ máa wòó nítorí kò fi bẹ sì ààyè láti má fọwọ́ ko nkan to bẹẹ
Olorun Oba dakun lawa lọ́wọ́ ejò ayé maje kesu ó lágbára lórí ìṣẹ̀dá èmi àti ìwọ àmín

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 KINI WON PE NI ABILU. Abilu ni ise buruku kan ti aye ma nse si eniyan . to ba je obinrin ni won sa abilu si iru obinrin be koni ri oko fe rara ibaje omoge tabi adelebo bi won she ngbe ni won a ma gbe ju sile tabi ko ma ri okunrin pe rara to ba si je okunrin ni koni ri iyawo fe rara awon moju ni obinrin amawo tabi ki won ma fi she jeunjeun... Hmm abilu koki se amutorun wa rara omo araye ni won fi ma nse ara won oko ma nfi abilu kan iyawo beni iyawo gan ma nse abilu si oko papa julo awon to won ba to korawon si le won ma nlo abilu lati maleje ki iru eni be leri oko tabi iyawo Miran femo .... Beni eni ti koti fe iyawo tabi loko ma nse agbako abilu lati owo awon abilu eni tabi lati fi sesan iwa odale fun ololufe toba dale ife hmmmmmm ju gbogbo elo oloun se maje kako si pakute aye oooo. Amin ooooo ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Nile yoruba won npe omi kan ni omi ajipon tabi omi aifoun pataki omiyi won man fi n wure fun eniyan tabi we fun eniti oro re ba kudie kaato ton sise bi Erin Eliphant ton Je ije eliri Awon onirawo omi loman saaba lo omi yiju sungbon gbogbo irawo lole loo nitori maje mu towa nibe Bio bapon omi ajipon kale boya lati inu kan nga well water tabi ni odo tonsan tio si bu iyo sinu re ti owa fi we pelu oyin tio si se adua sii daada kio to gbeewo baluwe tio bale se bee fun ojo meje asiri aye re tio tu sie lowo lati oju orun re ti waa siri ona abayo Bakan naa bio ban woju oluwa fun Omo bibi tabi ise bo lowo re tabi eniyan sese gba shop tabi ile tuntun awon ojogbon man lo omiyi lati fi fo ibe oro eni naa yio si maa to konisi idena kankan fune emi kemi kan koni wo ibe Bakan naa odara lati maa fi omi ajipon se adua daada kia ni adua ni yio tete maa gba OLORUN OBA DAKUN JEKI AYE MI O TORO NINI BI OMI AFOWURO PO AMIN. ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592

Monday, October 15, 2018

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Ẹyin Ọmọ Ológo tiẹ̀ wá nínú group yí mofe kie tún kó ẹ̀kọ́ pàtàkì towa lára ẹja Aro òun náà ni ẹja Abori, Ní ọjọ́ die seyin moti sọ nípa ẹja yiri àti ipò towa ninu awon ẹja pátápátá oman yami lénu tiẹ̀ ẹlòmíràn bani irawo omi ogbodo maabo òrìṣà Osun rárá o Ọlọhun Ọba toda ayé otidaaye láti ìgbà tí eda kàn kan kò tíì sí lorile ayé mowa je koye wá wípé eda ènìyàn ni Ọlọ́run ọba fi ṣe oga lórí gbogbo nkan pátápátá tí Ọlọ́run Ọba sije Alakoso ayé àti ọrun moti je koye wá wípé àwọn ẹ̀dá kan wà toje wípé inú omi ni wọn ti nse èmi títí wọn bẹẹni àwọn kan tún wà tí wọn nse èmi wọn nínú afẹ́fẹ́ nínú gbogbo àwọn ẹ̀dá yí ari eyiti òùngbẹ orile ayé èyí ló fi jẹ wípé àwọn iran tio Tara omi jáde pò daada tí wọn sì ń Semi lókè eepe ìtumò ẹja Aro nílé Yoruba ni wípé bí àwọn ojogbon bá fi ṣe aájò fún ènìyàn wọn aṣọ wípé aro aromo ọ bakan naa nínú gbogbo ẹja ẹja Abori ni Olórí fún gbogbo ẹja Oropo laarin yí Bio baje eniti oun lo irawo iseda omi òní láti jinnaa sì ẹja Abori yí tio bafe tete rono abayo Lori oro ayé rẹ bí ọba nje ẹja yí ọtí fún àwọn èmi òkùnkùn láàyè kiwon ó wọnú arare láti ṣe ìṣekuse nínú àyere tí gbogbo nkan yio si maa daru moe lowo díè díè beena ni kò dára koo máa jẹ Alakan inú òkun eleyi yio maafa inú rirun tàbí inú kíkan tàbí kio ni àrùn ijú tí yio si dènà Àìrí omobi máa dànù dúró díè nibiyi ao tún máa tesiwaju lorie Eku ojú lọ́nà EO gbádùn mi daada oro inú Group yí kii se ṣeré ṣeré ó eko pò nínú ẹ ẹ gbìyànjú kie má aka àwọn nkan inure daada lágbára Ọlọhun aoni mo ìnira amin ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Bi eo ba gbagbe ati soro Lori orisirisi a won nkan to romo irawo omi ati ti ti ina sungbon Lara awon eyiti o tun romo titi omi ati ti INA lao tun ti tesiwaju mosoo siwaju wipe lara isoro ti eniti obaje oni rawo omi tun saaba man ni ni oko orun aya orun ati Omo orun meteeta lao soro Lorie oya emaa bami kalo opolopo ni komo nkan ti won npeni oko orun tabi aya orun ati Omo orun won man ro wipe nkan kekereni bio baje Omo egbe tio tini oko tabi iyawo lati ode orun wa yio soro fun iru eni bee kio to ri oko gidi Nile aye tabi iyawo gidi koda bio baloko tabi ni iyawo won oniipe ko arawon sile nitori alijannu yi buru pupo kii tete GBA fun won eru egbe ti won man di fun won da gege bi eni tio je enikan ni gbese 50,000 ti oni gbese wan beere owore tio wa n bebe kio ma binu tio si n fun ni Owo yi ni bi two two kobo se emo wipe gbese yi sipo Nile koja Bose nsan Owo yi tio wa ni dandan afi ki oun ogba gbogbo Owo oun lowo eniyan tio wan bebe tio tun da ojo Miran fun kio tun wa sebi emo wipe eniti aje lowo koni gbagbe bee gele ni oko orun ati eru egbe didi je oun lefi man ri opolopo eniyan bio bade aimoye ona won a ni kio deru egbe laimoye igba ona abayo ni kio GBA arare lowo alijannu yi patapata eleyi naa tun je okan ninu ounti won fi man so fun enitio bani aya orun tabi oko orun wipe kio fe boya eni tio ba se IFA tabi tioje alagbara eniyan nitori atile gbaa lowo Ogun Alijannu yini Lara a won akoba tio man se fun eniyan nikii jeki Owo eniyan o tete GBA ire Oman dina mo eniyan paapaa ojo tio bati ba eniyan lajoose po ti eni naa waatun ni ajoosepo pelu eniyan Miran loju aye inu man bii pupo yio maa wa wona lati da wahala si orun eni naa bii kio maaje gbese kiogbe oja kale kio mata toro koni ba kobo jin lowoe bio bani adeun pelu enikan latife aarin won konipe daru IJA tikoni itumo ni yio de si aarin won awon okunrin akan maa baasun kiri lasan ni koni jeki ori ibujoko gidi tabi iyawo gidi sungbon gbogbo ibiti obade laye omo ologo ni won yio maa peee tio baje eniti obati ri itusile Lori aya orun tabi oko orun yi won yio wa beere lowo a won egbere wipe kini nkan tiwon omaagba bii saara won leeni ki omaako awon omode ati agbalagba lenujo ni odoodun kio Dana ounje funwon inu won man dun si iru nkan bayi koda elee mase saara yini deede date ojo ibiyin odara pupo bakan naa ao tun tesiwaju Lori a won Omo orun Gbogbo ABIYAMO ayé ao ni sagbako lowo awon emi okukun ayé ó Àmín ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.#

Irawo Ina,seri awon irawo ti anso yi je awon irawo to ni agbara pupo, tori ina ti won je, wonje kosemani, olorirere ati oninurere niwon, won je eni ti ola owo pupopupoju, won oni ahun rara, ina kuna won si ma npoju, awon kan ninu won ti e wa tojepe won nife si eso ara ati ti ile pupo, gold ni won ma n fi owo won ra, tori kosi ibi ti awon irawo yi ade ti eoni mon wipe eni nla kan de, iso wo soro won ati ise si won ma n fi won han lopolopo bi eniyan nla, oninu fufu niwon won de ma n ni agidi pupo, awon kan tie wa ninu won tojepe ti won ba nife si oun kan, ti gbogbo eniyan aye yi bawa nso funwon wipe nkan yi kodara, won oni gbo rara, ayafi igba ti won ba to kan abuku bo nidi nkan yen ki oju won toja,won ki gboran boroboro tinu mi ni mase sipoju fun won,won sima ntete dara de eniyan, idi niyi tofi jepe opolopo igba ni awon eniyan ma n dawon, won o ni ori ore rara kosisi ibi ti won ade ti won oki lara won,tori awon kan ninu won, gbogbo ibi ti won ba de ori ni won ma n saba fe je, eyi gan losi ma n fa ogun ati ota pupo fun won, Tori won ma n saba ni ebun pupo pupopupoju, awon kan ninu won bi oba ni won ma n fe se ni gbogbo igba, ojogbon sipoju ninu won, tori ogbon ori won ti poju, awon kan ninu won sima npa sege ninu iro, bi ijapa ologbon ewe ni won se ma nse, won si ma n wadi oun toba se kolofin pupopupo,won si ma n ni ase lenu bi oro lna se ma nmu igi idana beni ase enu won ma nmu Ile, agaga ti won ba fi ibinu soro, oma nsele warawara ni,awon kan ninu won kibimon pupo,won kisi ni iyawo pupo, ojukan ni ada won ma n ni, sugbon awon kan ninu won ma n ni ojukokoro ati afarawe, idi niyi ti won fi ma n se agbere tabi ni iyawo pupo,tabi ki won muti amupara, afarawe lasanlasan ni eleyi, tori koba irawo won mu, sugbon awon kan ninu won le mu igbo tabi siga ju eni keni lo ninu aye yi, tori ina ti irawo won jeyi loma nfun won ni anfani lati le mamu be ,ayafi eyi ti oba mon olorun ni kan ni koki n gbena gori ota ninu won, won si ma n feran ounje jije gan, ati okunrin ati obinrin won kosi eyi ti ki saba mon ina da, won si ma n mon obe se pupo ju awon irawo toku lo, won de ma n ni emin ati sin olorun, won si tun ma n ni Ife si ise olorun, lati kekere won ti awon obi won bafi ese won mon ona olorun, tori gbogbo ise buruku aye yi owo awon irawo yi loma nwa, won ma n ni igboya pupo, oun loun ti won ba si mon amon ju ni won ma n mon, to ri iwadi won ma npoju nipa nkan tanba nife si, opolopo ninu won ni owo won tete manji si owo sugbon won oni fi jonkan monle, odigba ti owo bawa safere ni owo won ki won to wa ma ronu oun toye ki won ti fi owo se,idi niyi tofi jepe nigba ti won aba fi pe omo 35/40,years,obinrin toje afefe tigbodo wa ninu Ile eyi toje okunrin won tabi okunrin toje afefe ti gbodo gbe eyi toje obinrin won sile gege bi iyawo, tori asikoyi yi ni oma nfe re irawo won ti irawo won si ma n fe wo okunkun, sugbon ti won ba ti ni afefe bi iyawo tabi ni oko, oun ni yio ran irawo won lowo lasiko yen lati le bawon fe ina irawo won jo pada, sugbon eyi ti koba mon asiri yi yio lero wipe aye ni oun se oun, awon kan ati e tun masope bi awon oba ni owo awon oni fe iyawo tabi ni oko, besini idamu won yio ma posi aya igba ti won ba to ri irawo afefe ti yio ran irawo won lowo ki nkan tobere si pada bo si ipo,awon toje obinrin won, ki won ma ni suuru, tori won oki fe ni suuru, won ma nfe pase fun oko won ni, tori won ma n ni owo ju oko won lo, sugbon opolopo won ni ki mon wipe oko won na lonba won dana irawo won, tori e ni opolopo won se ma nfe control oko won,idiniyi ti won ki fi saba gbe Ile oko, tori kosi okunrin toma gba ki obinrin ma pase le oun lori, ayafi eyi toba jepe won ti fi pata lu lori abi won ti gberu lati eyin nikan loku ,fun idi eyi awon obinrin won gbudo ni suuru ati iteriba ki won bale pe nile oko dada, awon kan ninu awon irawo yi ma gberaga pupo, won si ma nfe lo agbara ati ipo le awon eniyan lori, sugbon ki won sora fun eleyi tori olorun nikan lole gbe eniyan de opolopo layeyi, awon kan ninu won ma n ni fe si ibalopo pupopupoju, awon kan ninu won si ma n feran eran jije, ki won si sora fun iwa emi ni moto bayi ni mo da bayi, ojo ori re won ni Monday, Wednesday, Thursday, Saturday and Sunday, awo aso ti odara ju fun won ni, pupa foo, ati awo olominosan, pupa ofefe, ati funfun,ki won ma wo dudu rara o, tori kobawon lara mu rara ati rara, okereju won gbudo mani ibalopo pelu oko abi iyawo won ni ekan abi emeji ninu ose, tori oro tiwon koja mofe ni isera ose meta tabi osu kan ti won ba sebe gbogbo nkan aduro si ojukan ni, sugbon ti won base nsumon oko tabi iyawo won ni afefe won ama fe irawo won o dada ni gbogbo igba,iseti oma bawon lara mu ju ni obe jije tabi ise jjo bi imule, ori bibo na si dara fun won, ise asela won ni, ise jagunjagun ni gbogbo ona, kobaje tori Ile tabi tori omi tabi tori afefe, tabi ise olopa tabi ss tabi asogba, ki ama sise ni ile Itura tabi ki ada ile Itura sile, ki ama se ounje ta ni gbogbo ona, ki ama ta aso tabi ran aso, ose sise, tabi irin ikole ni tita, buredi tita tabi ki amase, awon na ni carpenter tabi mechanic, ojise olorun tabi alfa tabi babalawo, won sise nile ise Nepa tabi panapana, tabi gbogbo ise inu orun pata isewon ni, asiwaju sini won ninu oselu, pupo ninu won igi iwe niwon, awon ni won ma n saba ni professor,, ati gbogbo ise toba ti jemon ina ni ise asela won, sugbon iyawo tabi oko ti odaraju funwon ni irawo afefe,tori ti won ba fe irawo min, nkan oni saba lo dede fun won.

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Eku ojumo eyin ololufe abala ikan ni yi ewo aworan yi daada eori wipe Ibi omo placental ni kini anpeni ibi omo ibi omoni bi omo tuntun bajade tan ibi omo loku ti yio jade meji meji ni olorun oba da nkan sile aye gbogbo ibi ti ayo basiwaju ibire na yio si Maa telee ai mo itumo ibi omoyi lojeki wahala o po ninu aye loni bio ba sin ibi omo si oju ona omo naa yio Maa seru egbere nio bio basin ibi omo si akitan aye yio Ma korira omo naa bio basin ibi omo si inu agbo ogede emere odaju omo ni yio ya bio baju ibi omo sinu salanga toilet I Korira yio po fun omo naa lawujo bi Oba gbe ibi omore fun ajaje omo naa yio ya alagbere bio ba ri ibi omo re si eti odo tabi ibi tio tutu oore idun nu yio po ninu aye omo naa idi ni yi ti e fi ri ti awon babawa fi man ri ibi omo si baluwe gbogbo nkan naa koni ogun awon nkan miran tun wa to jemo iseda aye wa oro ESIN ni awon Eniyan man gbe sori ni oro aye won fi man daru mowon lowo ewo Ile aye loni bie bade Ile alawo tabi Ile Alfa tabi pastor won yio ni omo ologo nie sungbon Aimoye ose Aimoye aawe Lotigba kosi ona abayo kankan fun un Bio ti n kuro ninu ogun kan lo tun nbo si inu ogun miran bakan naa bio bagbe PLACENTER junu sinu agbara ojo bayowu ki omo na o pe to laye agbara ojo ni yio gbee lo gbogbo oro ti mo so yi eda kun ebi awon tio je ijinle agbalagba won a tun so pupo funwa lorie die ti mole so niyi ninu e ejeki amaa gbo ikilo ao ni rogun i daamu aye nkan ti ènìyàn obamo kosi ese lorie gbogbo ìbí yowu tí oro ayé wa bá Kusi jowo Eleduwa bawa tún bẹ́se mafi wá Seru egbe wá láyé Àmín. ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

Sunday, October 14, 2018

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 EWU TOWA NI NÙ IBALOPO PART TWO NÌYÍ (1) Kódà rà láti máa bá obìnrin Olobinrin lasepo tàbí ọkọ èlò miran nítorí ole fe ikú ojiiji ènìyàn le tí be kosi panpe iku ma gun bakan naa Ọlọ́run kò fara mọọ (2) Kódà rà láti máa ní asepo nínú igbó nítorí tí ejò bá gba orire oman fà àrùn ẹyin dídùn lọ́jọ́ àlè (3) Kódà rà láti máa lasepo laarin ona tàbí láárí(passage) inú ilé oman fà àrùn Afẹ́fẹ́ tí wọn pé stroke lọ́jọ́ àlè fún ènìyàn (4) Kodara láti máa lasepo pelu Obìnrin nínú ilé Ahoro tí obaje wípé àwọn eleye 'n se ipade nínú ilé Ahoro náà olewu wọn man dá irin ajo ayé ènìyàn ru nio (5) Kódà rà láti máa ní asepo létí odò nítorí àwọn Alijannu omi kiwon oma baa se ènìyàn ni jamba Ọlọ́run Ọba gbogbo ẹse tí àti dá dakun forí jin wá kio si ṣàánú fún wa kio yọnnu wa Amin ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 EWU TOWA NI NÙ IBALOPO PART TWO NÌYÍ (1) Kódà rà láti máa bá obìnrin Olobinrin lasepo tàbí ọkọ èlò miran nítorí ole fe ikú ojiiji ènìyàn le tí be kosi panpe iku ma gun bakan naa Ọlọ́run kò fara mọọ (2) Kódà rà láti máa ní asepo nínú igbó nítorí tí ejò bá gba orire oman fà àrùn ẹyin dídùn lọ́jọ́ àlè (3) Kódà rà láti máa lasepo laarin ona tàbí láárí(passage) inú ilé oman fà àrùn Afẹ́fẹ́ tí wọn pé stroke lọ́jọ́ àlè fún ènìyàn (4) Kodara láti máa lasepo pelu Obìnrin nínú ilé Ahoro tí obaje wípé àwọn eleye 'n se ipade nínú ilé Ahoro náà olewu wọn man dá irin ajo ayé ènìyàn ru nio (5) Kódà rà láti máa ní asepo létí odò nítorí àwọn Alijannu omi kiwon oma baa se ènìyàn ni jamba Ọlọ́run Ọba gbogbo ẹse tí àti dá dakun forí jin wá kio si ṣàánú fún wa kio yọnnu wa Amin ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Itesiwaju lórí ọkọ ọrùn tàbí aya orun bakan naa bí ase lè tètè dá Elegbe ọmọ mọ àti àwọn ìṣòro kọ̀ọ̀kan towa lábé irawo kọ̀ọ̀kan tí ó ti fà ìṣòro sínú ayé àwọn ènìyàn lao mẹ́nu bá yí ni sise ń tẹ́le, Àlá koko ninu awon opolopo ọ̀rọti moti kọ́kọ́ só seyin nípa ọkọ ọrùn wípé ẹniti o ba ni ọkọ ọrùn tàbí aya orun iru eni bayi òní irawo omi lo gbodo je sungbon ẹniti kò baje onirawo omi towa ni ọkọ ọrùn ìṣe ọwọ àwọn eleye lèyí wọn ofe kí orile ọkọ joko sì tàbí kio lomo laye ni sungbon tio baje wipe ẹniti òní irawo omi ni ìṣòro ọkọ ọrùn tàbí aya orun eleyi kii se yeye rárá confirm nio àìmọye nkan ni ẹniti òní ọkọ ọrùn Man fi ṣe ìbúra latode orun wá èlò miran Man fi ọjọ́ ikùn lè búra, tàbí ojo ìgbéyàwó bakan naa ojo ikomo jáde àti beebee lọ nje ó mọ wípé kodara ki ẹniti òní ọkọ ọrùn ó sáábà máa gba orita mẹta kọjá ní gbogbo ìgbà nítorí ó Man dúró de Ololufe rẹ toba je ìyàwó rè titaye nibe bakan naa ọkọ ọrùn kiije ki oogun oje fún obìnrin tàbí ọkùnrin tí ó bani aya orun ao máa tesiwaju sii lorie eleyi jẹ( Part one) GBOGBO wa ao ni fesu soko laye wa Amin. Edakun ema beere ibeere ninu comment, Mi o ni da eyan lohun mo nibe, Eniba fe beere Irawo re ki o pe ago mi lati dalohun ibeere re. ESANU OMO ARISEKOLA FUN ONA ABAYO TABI IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.

Wednesday, October 10, 2018




Save a soul

Give and it shall be given unto you , good measures, pressed down, shaken together and running over.

Dear colleagues, fellow Nigerians, the young man in the picture above is in desperate need of your help. His name is Temiyemi Sherif Alao,  26 of age, HND 1 Student of the Pharmaceutical Technology Department, Moshood Abiola Polytechnic, Abeokuta.

About a weeks ago, he was involved in an accident, which involved a trailer and a motorcycle, in the course of the accident he had chest internal injuries called Cardiac palpitations. Which has caused his hands to be swollen and Tiers in the leg.

He is scheduled for appointment for next month. October 28th, 2018.

For Medication and Surgery, Temiyemi is needing 350,000 naira.

Please Temiyemi sheriff alaodeen is in dire need of our help, no amount is too small. Please help us save Temiyemi Sherif Alao before it's too late. I call on all Mothers, fathers, sisters, brothers,  to join and help support this cause.

Together we will save Temiyemi Alaodeen Sherif.
His account number is:

TEMIYEMI SHERIF ALAO
6550187300
FIDELITY BANK.

God bless you.