ASIRI IRAWO EDA
Monday, October 29, 2018
WARNING 🚧 WARNING 🚧 WARNING 🚧 EYIN NI OFIN EGBE (ASIRI OJO IBI IRAWO LATI JANUARY TITIDE DECEMBER GROUP) 1. AO FUN ENIKENI LAYE LATI MADAHUN SI ORO TOBA TI JEMO IRAWO NINU GROUP AYAFI AWON ADMIN GROUP ENITI O BA RUN OFIN YIO BA ARARE NI ITA. 2. A KO FE ORO ABUKU TABI ORO ARIFIN LARIN OMO EGBE SI OMO EGBE YI 3. KO SI ANFANI FUN ATEJISE TI KO JO MO TI INU YARA YI 4. KO SI AYE FUN ENIKENI NINU YARA YI LATI POLOWO OJA TABI FI LETA INVITATION GROUP SINU YARA YI LAIGBA ASE LOWO OLUDASILE TABI ADIMN 5. IFOWOSOWOPO GBOGBO WA SE PATAKI LORI ISOROKISORO TI OMO EGBE YI BA NI 6. FUN IRUNI LOJU IBEERE EPE SORI AWON NUM 08102159160, 0814774849, 08127761592.
Sunday, October 28, 2018
Ìdí tí àwọn ènìyàn fi kò orisirisi eso losi etí òkun nìyí moti jeko Yéwá wipe Alijannu inú omiyi Obìnrin ni tiosije Olomo pupo Alijannu omi tioje ọkùnrin náà wá àwọn Alijannu omiyi feran èso láti máa jẹ pelu orisirisi nkan ti àwọn ọmọ wewe manje bíi sweet, ireke, Aadun, Ọ̀gẹ̀dẹ̀ epa, guguru, wàrà tútù àti oyin líla, Sugar, iyọ̀, Chweries, àti bẹẹbẹẹ lọ yini àwọn Alijannu omi yìí man feran daada Sungbon wọn feran èso pupo ju bí ona badi mo ẹniti oje on irawo omi tàbí ìṣòro kan wà níwájú rẹ bio base irú saara bayi àyípadà yóò dé bàa ní kíákíá bí kò bá sì idiwo ota nínú ọ̀rọ̀ ayé rẹ bo obase irú saara yi yóò tètè rí ìtura ao toju orisirisi èso yio dáa sínú odò lanla sungbon asiko tó bá ṣe saara yi aṣọ funfun ni yóò saaba máa wò sun ao tún máa tesiwaju lorie nínú live program lágbára Ọlọ́run ọ̀rọ̀ ayé gbogbo wa ni yio loju tú bí ase nfe amin
Friday, October 26, 2018
EKUN_RERE_AKOSE_JAYE_OJO_IBI_RE 🌟🌟🌟🌟 Gbogbo wa lamo oruko aworan yi wipe igbale tabi owo lonje Aimoye igba ni moti soro lori die lara iwulore yato fun kia fi gbale ona tio gba wulo po gan an Bio baje eniti oma n saaba la Alakala ni ojo ojumo kio gbe owo tabi igbale duro gege bi eleyi ti enwoyi se duro leyin ilekun behind door inu yara tie fee sun mofi olorun oba bura fune wipe alijannu buruku kankan koni wole bee sini alaburu kan kan koni wa fune mo eyini lara ogbon atinu da awon babawa e danwo bee leo ba a asiri aye ni aye oni koju ija dawa amin ESANU OMO ARISEKOLA FUN IBEERE EPE SORI NUM YI TABI WHATSAPP# #08102159160 OR 08127761592.
ITESIWAJU LÓRÍ ISEDA YẸPẸ AWON ÌṢE SI ẸNITI OBANLO IRAWO YEPE IRAWO YEPE ORÍṢIRÍṢI LOWA IRAWO YEPE OMOWA IRAWO YEPE ASALE DESERT WA BÁKAN NÁÀ IRAWO YEPE ÒKÚTA WA AO MAA MẸ́NU BÁWỌN NI Ọ̀KỌ̀Ọ̀KAN 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟 Bí ènìyàn je eniti onlo iseda YẸPẸ OMI irawo yí dára pupọ iseda òní yepe OMI ATI IRAWO OMI ṢE DEEDE ARÁ WỌN ṣùngbon ìyàtò die die lowa pelu wọn Ẹniti o ba fẹ irú ènìyàn bayi Wonkii ni ènìyàn lára iba gbé pò wọn a máa tú ènìyàn lára kódà wonle fi ojú wọn to rẹ fún ènìyàn nibiti inú won dára de Won man pa àṣírí mo daada àǹfààní sípò lára wọn kosi eniti kole báwọn gbé sungbon wọn kí ìfẹ́ ìnira bíi ìjà tàbí nkan ariwo rárá gbogbo ọmọ bibi man pọ lára wọn eyiti oba ni ida dúró tabi kò tètè rí ọmọ bí tàbí tí kori ibú joko ìṣe ọwọ àwọn èmi òkùnkùn ni tabi ki eni bee omaaje eewọ tiko bá iseda rẹ mú wọn man kò onílé àti àlejò mọ́ra sungbon ika ni ọmọ aráyé man fi dípò rere fún wọn Bí ẹni tobanlo iseda yí bawa pelu ẹni ton ta oja ọjà ẹni náà yóò sì máa tá nítorí iseda owó ni iseda yí latara àwọn iseda yí ni àwọn ọmọ ẹgbẹ́ emere Olokuta tí man jáde awon ọmọ ẹgbẹ́ yí burú pupo agídí wọn a sì máa pọ wọn man gbé san lára ẹni toba dojú ìjà kọ wọn ìṣòro ibujoko tàbí nínú ìyàwó gidi sílè man pọ fún won eniti oba ni owo lọ́wọ́ nínú wọn kii sábà tètè rí ọkọ gidi eyiti koba sì tete lowo Ogbodo jìnnà sí ìwà àgbèrè nítorí gbogbo ọkùnrin toba ni àjọṣe pò pelu rẹ ni ona yio maa mafun aomaa tesiwaju lorie iseda ẹni kọ̀ọ̀kan wá koni gba bode ẹ dakun gbogbo nkan ti mo sọ̀rọ̀ lorie dale lórí eniti oti mọ irawo rẹ tele sungbon tofe mọọ síwájú sii Édakun kí enikeni omaa send date of birth kankan sí mio ẹni toba fe mo irú iseda rẹ kò béèrè níbi to ban losi Eseun
Orúkọ èwe yí a máa jẹ ewe péré gun Oje ewe to gbajúmò dáàda àwọn ojogbon ènìyàn manloo fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ igbiyanju pàápàá wọn man fi èwe yi re ègún kúrò lórí ènìyàn, wọn man fi èwe yi yo ọwọ àwọn èmi òkùnkùn lára ènìyàn wọn man fi èwe yi wo àìsàn lorisirisi Sungbon kókó àti pàtàkì tó tún sá pamó sára èwe yí niyi Igi èwe yí jé ibiti àwọn ọmọ emere ọmọ má ń saaba ṣe ìpàdé pupọ igi abàmì ni igiyi ibi tí wón bá gbìn èwe, yisi wọn man fi igiyi sàmì ibiti wọn ba gbìn igi yisi ni ìwúlò tó tún wà lára rẹ fún gbogbo ala biya mo nìyí Bí ọmọ kékeré banke láìnídì pàtàkì kan ao gun èwe yí lodo daada ao fò odidi agbon kan sii ao fi gba omi Ara èwe yí ao wa ta oyin tàbí epo pupa sii ao máa fún Ọmọ náà mú ao sì tún máa fi paa lára tí obaje wípé àwọn ẹmi òkùnkùn londa ọmọ náà láàmú kíá ni wọn yio kúrò lára ọmọ yí Bakan naa bí wàhálà bá pò fún ènìyàn lórí ìdààmú àwọn èmi òkùnkùn ao ja ewe yí ao tún wà egbo rẹ pẹlu isu ògiri ṣáko eepo obo, egbo tude, ao gun papo kí iru ẹni bẹẹ omaa fi wé ọ̀rọ̀ ẹni náà yio lojutu sì rere lagba Ọlọ́run Ọlọ́run Ọba ìwọ lala gbàrà mafi ìjẹ imuwa sowo ọta wá kio lana ire fún ẹni kọ̀ọ̀kan wá amin
PATAKI OSEYI ATI ÌWÚLÒ RẸ NIYI Bí ènìyàn banmu amubo lori ọkọ tàbí aya pupọ ose yí wúlò fún irú ènìyàn bee Bí ènìyàn bá ń fi ara kò òwú Alantaakun pupo ju owulo fún ènìyàn bee Bí ota bá pò fún ènìyàn tí wọn ń korira ènìyàn owulo fún irú ẹni bee Tí ènìyàn bá dawole nkan ti nkan naa kiipe daru mo eniyan lọ́wọ́ owulo fún irú ẹni bẹẹ Bí ènìyàn bawa ni irin ajo ti ofe kí òun ó tètè rise kio má rí alatako òwú lo fún ẹni bẹẹ Obìnrin tí ó wà nílè oloro gùn tí wàhálà pò nibe bóyá enikan lépa èmi rẹ owulo fún irú ẹni bẹẹ Kii jeki ọfà ota ó wole sì ènìyàn lára òsì man dènà asasi Bí ènìyàn báni àwọn ọmọde lọ́wọ́ odara fún wọn nítorí ààbò Ọlọ́run Ọba Eyonu gidi ni a sina gidi ni bakan naa otun ń dènà alakala Otun dara fún Obìnrin tí koni ibu joko Owulo fún oga ilé ìṣe tàbí ọmọ ek ose tàbí ọmọ ilẹ̀ ìwé kosi ọjọ orí tí kólé loo bakan naa ọmọ ìkòkò lè loo Orúkọ Ọlọ́run lafi see Otun wúlò fáwọn nkan pàtàkì kan tí ao lè máa ṣàlàyé rẹ bayi eniti o bára ose yí lao ṣàlàyé gbogbo rẹ fún bakan naa kose pín sí méjì ori kan ose kan nio Kiise ose yí nìkan nio pelu ipara rẹ nio má fojú di I wípé orí net loti bàa pàdé ó àwọn tó dáa mi niwon ni tun fe ki see jáde owore kopo rárá ìwọ tio bati fe nínú èyí ni àwọn tí èlé rí ose yí ra lọdọ wọnv tiwọn yio tún ṣàlàyé rẹ fún yín yekeyeke bie sele loo (1)EO ríi ra ni Bayeku Community bus stop Cross to other side and ask for Alhaji Solaudeen, 08027380717,08177396458, Ikorodu Lagos (2) Enter bus to Ajah alight at Agungi bus stop cross the road to other side then, take bike to Ajiran drop at Ojomu Central Mosque Ask NUMBER 17 Bakare Avenue Ajiran Eti Osa Lagos , 08030473635, 08175929955 (3) AKINOLA STREET NUMBER 29 Bariga second room by the Wright Lagos Sheik Luqmon Olasunkanmi Ayandare +2348089038658, +2348032983298 +2348133155111 +2347059780034 +2348179391932 +2348180023385 +2348089522187 HOME ADRESS AKINOLA STREET NUMBER 29 Bariga second room by the Wright Lagos Nigeria 🇳🇬
AWON ISESI KỌ̀Ọ̀KAN TOWA FÚN ÒNÍ RAWO AFẸ́FẸ́ NÌYÍ ATI AWON IWA WỌN LỌ́KÀN Ó JO KAN PART ONE 🌟🌟🌟🌟🌟🌟🌟💯🌟🌟🌟🌟🌟🌟 (1) Àwọn isesi eniti o ba ni irawo AFẸ́FẸ́ man jọ isesi eniti Obanlo irawo omi laimoye ona ìdí nìyí tofi je wipe bí èlò miran bá béèrè lọ́wọ́ àwọn ojogbon wipe oun fe mo irú irawo abawaye òun tiwon yio so wipe irawo Afefe lonlo sungbon toje wipe irawo omi logbewa sáyé nítorí irawo afefe oríṣi risi lowa eniti Obanlo irú irawo òní méjì bayi lan peni irawo Afẹ́fẹ́ omi odara púpò ayé irọrun ni ẹni tí náà yóò gbe awon eniyan bayi kose fi ara we nítorí lailo oogun kan kan gbogbo nkan yio maa rọrùn fún un láti ṣe láyé èmi wọn Asi máa gun dáàda (2) Àwọn ẹni toba je onirawo Afẹ́fẹ́ omi oman wù wọn láti tètè di ènìyàn 'ńlá laye oore nla man sele sinu ìgbésí ayé wọn bakan naa wọn kí ìfẹ́ kí ènìyàn ó di àwọn lọ́wọ́ biwon bafe se nkan laye lati kékeré àwọn ọmọ bayi man tẹnu mo ọ̀rọ̀ púpò ju biwon bafe ki bàbà àwọn tàbí ìyá àwọn Ora nkan fún wọn gbogbo igba niwon yio ma tẹnu mọ nkan naa (3) Bi wọn ba bí àwọn ọmọ bayi nibiti àwọn ìka ènìyàn bá pò bá yowu kí wọn o pọ to òun ni yio Segun gbogbo wọn sungbon wọn ò ní jeki irú ẹni bẹẹ otete ri aje lo bose fe sungbon tio bati kúrò nínú ilé bẹẹ tá bí nínú ìlú bẹẹ yio tete rise (4) Àwọn ọkùnrin bayi tàbí Obìnrin bayi gbọdọ kunfun adua daada nitori àti rí ọkọ tàbí ìyàwó kiise wàhálà ṣùngbon ìṣòro àti rile ọkọ gbé wọn loje ìṣòro wọn man koju ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣòro nínú irin ajo wọn ọmọ aráyé man nílò anfaani wọn sungbon àwọn kiiri àǹfààní gba latodo ènìyàn Ayaafi odò Ọlọ́run Ọba Continue Oore ayọ̀ ẹni kọ̀ọ̀kan wá yóò máa lekun sii 'lojo gbogbo amin
Subscribe to:
Posts (Atom)